Okey Bakassi
Okechukwu Anthony Onyegbule , tí gbogbo ènìyàn mọ̀ ssíOkey Bakassi tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹta Oṣù Kẹwàá Ọdún 1969 ní Ìpínlẹ̀ Ímò jẹ́ apanilẹ́rìnín àti òṣèré orí ìtàgé ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà . [1] [2] Ní 2014, ó gba Àmì ẹyẹ ''Òṣèré tí o dára julọ ni ipa ìtèwáju eré (Igbo)" ni ẹ̀dá 2014 ti Best of Nollywood Awards fún ipá rẹ nínú fíìmù Onye Ozi . [3] [4]
Okey Bakassi
| |
---|---|
Bibi | Okechukwu Anthony Onyegbule </br> 3 Oṣu Kẹwa Ọdun 1969 </br> Ipinle Imo
|
Orilẹ-ede | Nàìjíríà |
Omiiran awọn orukọ | okey bakassi |
Omo ilu | Nàìjíríà |
Iṣẹ iṣe | Apanilẹrin |
Aaye ayelujara | https://okeybakassi.com/ |
Wo eleyi na
àtúnṣe- Akojọ ti awọn Nigerian osere
- Akojọ ti awọn Nigerian comedians
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ Egole, Anozie (3 February 2013). "I’ll always be a politician – Okey Bakassi". http://www.vanguardngr.com/2013/02/ill-always-be-a-politician-okey-bakassi/.
- ↑ Adegun, Aanu (5 December 2013). "Comedian Okey Bakassi, from grass to stardom". Archived from the original on 20 January 2016. https://web.archive.org/web/20160120174949/http://www.mynewswatchtimesng.com/comedian-okey-bakassi-grass-stardom.
- ↑ Izuzu, Chidumga (17 October 2014). "Tope Tedela, Ivie Okujaye, 'Silence' Win Big". http://pulse.ng/movies/bon-awards-2014-tope-tedela-ivie-okujaye-silence-win-big-id3205982.html.
- ↑ Oleniju, Segun (17 October 2014). "BON Awards 2014 Complete List Of Winners". http://www.36ng.com.ng/2014/10/17/bon-awards-2014-complete-list-of-winners/.