Okey Uzoeshi
Okey Uzoeshi /θj/ jẹ́ òṣèrékùnrin àti olórin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó gbajúmọ̀ fún ìkópa rẹ̀ nínú fíìmù Two Brides and a Baby, Blood in the Lagoon, Love and War, Something Wicked àti Couple of Days.[1][2][3][4]
Okey Uzoeshi | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 8 Oṣù Kẹrin 1983 Imo State |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | Federal Polytechnic, Nekede |
Iṣẹ́ | Actor |
Gbajúmọ̀ fún | Something Wicked, Couple of Days, Life of a Nigerian Couple |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeỌjọ́ kẹjọ oṣù kẹrin, ọdún 1983, ni wọ́n bí Okey, sí Ìpínlẹ̀ Imo. Ó lọ sí ilé-ìwé Birrel Avenue High School fún èkọ́ girama, ó sì lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Federal Polytechnic Nekede Owerri fún ẹ̀kọ́ gíga.[5]
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeÓ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i olórin kí ó tó bẹ̀rẹ̀ sí ní kópa nínú fíìmù àgbéléwò, níbi tí ó ti ṣàfihàn àkọ́kọ́ nínú fíìmù Fatal Imagination. Láti ìgba yẹn, ó ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù àgbéléwò bí Something Wicked, Strain, Couple of Days àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ
àtúnṣeÓ ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ láti ọwọ́ Best of Nollywood Awards (BON), Golden Icons Academy Movie Awards (GIAMA), àti African Movie Academy Awards (AMAA).[6]
Àtòjọ àwọn fíìmù tó kópa nínú
àtúnṣe- Fatal Imagination
- Couple of Days (2016) bíi Dan
- Life of A Nigerian Couple (2015) bíi Emeka
- Alan Poza (2013) bíi Kokori Oshare
- Something Wicked[7] (2017) bíi Abel
- The Sessions (2020) bíi Ejiro
- Blood in the Lagoon [8] (2015) bíi George Dibiya
- Sweet Tomorrow (2008) bíi Efe
- Battleground (African Magic Series) [9] (2017) bíi Ola Badmus
- Blood sisters[10] (2022) bíi Winston
- Two Brides and a Baby (2011)[11] bíi Maye
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Nollywood's Generation Next Actors (2)". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-08-06. Retrieved 2022-08-02.
- ↑ Okonofua, Odion (2021-07-27). "Pulse List: 5 Nigerian celebrities who used to be musicians". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-08-08. Retrieved 2022-08-02.
- ↑ izuzu, chibumga (2017-02-15). ""Something Wicked" packs a punch with a satisfying jolting end". Pulse Nigeria. Retrieved 2022-08-02.
- ↑ "Marriage is a partnership ― Okey Uzoeshi". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-05-09. Retrieved 2022-08-02.
- ↑ Writer, Rita (2021-04-30). "Okey Uzoeshi Biography– Life and Career of The Star". Pearlsnews – Top Entertainment News and Gossip in Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-02.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:13
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:02
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:22
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:12
- ↑ "Sisters Bound By Blood- Blood Sisters: A Netflix Nigerian Thriller". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-05-01. Archived from the original on 2023-04-04. Retrieved 2022-08-04.
- ↑ "Okey Uzoeshi | Actor, Producer". IMDb (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-06-19.