Okiemute
Olórin ilẹ̀ Nàìjíríà
Okiemute Ighorodje tí ó tún ń jẹ́ Okiemute, jẹ́ olórin ọmọ Nàìjíríà.[1]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeÓ bẹ̀rẹ̀ sí ní kọ orin láti ìgbà tí ó wà ní ọmọdún mẹ́rìnlá, tí ó sì kọ́ bí wọ́n ṣe ń tẹ ohun èlò orin lóríṣiríṣi.[2]
Ayé rẹ̀
àtúnṣeÓ ka ẹ̀kọ́ Linguistics and Communications ní University of Port Harcourt. Ó wá láti inú ìdílé tí wọ́n jẹ́ ẹni mẹ́fà, òun sì ni ọmọbìnrin kẹta nínú ọmọ mẹ́rin.[3][4]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Okiemute: It's not easy getting collaboration with big artistes, they think we'll take their shine". Lifestyle.thecable.ng. Retrieved 2020-01-19.
- ↑ "OKIEMUTE IGHOROJE - The Nation Newspaper". Thenationonlineng.net. Retrieved 2020-01-19.
- ↑ "MTN Project Fame winner, Okiemute decries stereotype in Nigeria music | P.M. News". Pmnewsnigeria.com. 2018-08-31. Retrieved 2020-01-19.
- ↑ Oshi Timothy (2016-09-25). "Okiemute Ighorodje emerges winner of MTN Project Fame West Africa - Premium Times Nigeria". Premiumtimesng.com. Retrieved 2020-01-19.