Okpa
Okpa jẹ́ oúnjẹ ilẹ̀ Ibo tí wọ́n máa ń fi ẹ̀pà Bambara ṣe.[1][2][3] Ó wọ́pọ̀ láàrin àwọn ènìyàn tó wá láti Ìpínlẹ̀ Ẹnúgu, wọ́n sì kà á mọ́ oúnjẹ ìbílẹ̀ Naijiria. Kìí ṣe àwọn Ibo nìkan ló ń jẹ Okpa, àwọn ẹ̀yà mìíràn máa ń jẹ Okpa pẹ̀lú ògì tàbí kí wọ́n jẹ ẹ́ lásán.[4][5] Orúkọ mìíràn tí wọ́n máa ń pe Okpa ni; ịgba àti Ntucha. Àwọn Hausa máa ń pè é ní Gurjiya tàbí kwaruru.[6]
Àwọn àwòrán
àtúnṣeÀwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Nigerian Okpa –How to make Okpa Food". besthomediet (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-09-07. Retrieved 2022-05-21.
- ↑ Chinedu, Saint (2022-01-06). "Reasons Why Your Diet Needs Bambara Nut Pudding (Okpa)" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-21.
- ↑ Lete, Nky Lily (2013-07-12). "Okpa : How to make Okpa". Nigerian Food TV (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-21.
- ↑ "Nigerian Okpa, Okpa di Oku, Okpa Wawa". All Nigerian Recipes (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-21.
- ↑ admin. "Nigerian Cuisine: Okpa; How to make Okpa". C.Hubmagazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-21.
- ↑ "OKPA". The Pretend Chef (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-07-05. Retrieved 2022-06-09.