Okwui Enwezor

Akéwì ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Okwui Enwezor /θj/ (23 October 1963 – 15 March 2019)[1] jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó jẹ́ olùtọ́jú mùsíọ́ọ̀mù, aṣàríwísí sí iṣẹ́-ọnà, òǹkọ̀wé, akéwì àti onímọ̀. Ó fìgbà kan gbéní New York City[2] àti Munich. Ní ọdún 2014, wọ́n tò ó pọl mọ́ ọgọ́rùn-ún àwọn ènìyàn tó ń ṣịṣẹ́ ọnà.[3]

Okwui Enwezor
Ọjọ́ìbíOkwuchukwu Emmanuel Enwezor
(1963-10-23)23 Oṣù Kẹ̀wá 1963
Calabar, Nigeria
Aláìsí15 March 2019(2019-03-15) (ọmọ ọdún 55)
Munich, Germany
Iṣẹ́Curator
Olólùfẹ́Jill S Davis (divorced)
Muna El Fituri (divorced)
Àwọn ọmọ1

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Russeth, Andrew (15 March 2019). "Okwui Enwezor, Pivotal Curator of Contemporary Art, Is Dead at 55". ARTnews (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 15 March 2019. 
  2. Rutger Pontzen, "I have a global antenna" (Interview with Okwui Enwezor) Archived 2019-04-24 at the Wayback Machine., in Virtual Museum Of Contemporary African Art.
  3. "2014 POWER 100". Art Review. Archived from the original on 29 June 2015. Retrieved 23 January 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)