Ológun Ojú Omi fún Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà

Ológun Ojú Omi fún Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà jẹ́ ẹ̀ka iṣẹ́ ogun tí ojú omi fún Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà àti pé ó jẹ́ ìkan nínú meje aláṣọ ogun fún Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà. Ológun Ojú Omi fún  Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà jẹ́ èyí tọ tọbi jù tí ó sì pójuwọ̀n jùlọ ní gbogbo àgbáyé[1][2][3] tí ó sì ní ohun ìjà jùlọ ní gbogbo àgbàyé.[4][5]

Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe