Olórí Ijoba ni Ààrẹ Orílẹ̀-èdè, Gómìnà Ìpínlẹ̀, Alága ìjọba ìbílẹ̀ tàbí ẹni tí ipò rẹ̀ ga jùlọ nínú ìgbìmọ̀-ìṣèjọba ìjọba àpapọ̀, Ìpínlẹ̀, àgbègbè tàbí ìbílẹ̀.