Olùsọdipúpọ̀
Ninu mathimatiki olùsọdipúpọ̀ (Coefficient) ni akopa alassodipupo ninu oro igbekaleoroexpression kan (tabi ninu eseese kan); lopo igba o le je nomba, sugbon bo ba se je ki i se ayipada inu igbekale na. Fun apere ninu
awon oro meteta akoko nitelentele ni awon olusodipupo 7 (éje), −3 (ẹ́ta), ati 1.5 (ókan àtìpín àrún) (ninu oro keta ko si ayipada, bi be olusodipupo gan ni oro fun ra re; a unpe ni oro adurosinsin tabi olusodipupo adurosinsin ti igbekaleoro na). Oro to gbeyin, eyun y ko ni olusodipupo kankan niwaju pato, sugbon a mu pe o ni olusodipupo 1, nitoripe isodipupo re pelu akopa na ko le yipada. Olusodipupo le je nomba, bi ti apere oke yi, sugbon won tun le je paramita inu isoro ti a fe wa ojutu, bi leta bi a, b, ati c ninu
nibi ti a ti mo pe awon wonyi ki se ayipada sugbon olusodipupo.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |