Olaitan Ibrahim (tí wọ́n bí ní 14 February 1986) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti eléré-ìdárayá tó máa ń gbé nǹkan tó wúwo. Ó gba àmi-ẹ̀yẹ onídẹ ti ayẹyẹ women's 67 kg ní 2020 Summer Paralympics, tó wáyé ní ìlú Tokyo, ní Japan.[1][2]

Olaitan Ibrahim
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbí14 Oṣù Kejì 1986 (1986-02-14) (ọmọ ọdún 38)
Oba Ile, Nigeria
Sport
Orílẹ̀-èdèNigeria
Erẹ́ìdárayáParalympic powerlifting

Ní ìdíje ti 2019 World Para Powerlifting Championships tó wáyé ní Nur-Sultan, Kazakhstan, ó gba àmì-ẹ̀yẹ onífàdákà ní ayẹyẹ women's 67 kg event.[3]

Àwọn èsì

àtúnṣe
Ọdún Agbègbè Ìwọ̀n Ìgbìyànjú (kg) Lápaapọ̀ Ipò
1 2 3
Summer Paralympics
2021 Tokyo, Japan 67 kg 115 119 127 119 Keta (idẹ)
World Championships
2017 Mexico City, Mexico 67 kg 110 120 120 110 Kejì (fàdákà)
2019 Nur-Sultan, Kazakhstan 67 kg 122 126 127 127 Kejì (fàdákà)

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe