Olajumoke Abidemi Okoya-Thomas jé omo ile igbimo asojú teleri,[1] o soju Lagos island/Federal constituency ti ìpinlè Eko labé egbe oselu All Progressive Congress(APC), o lo sáà meta nípò asojú.


Olajumoke Okoya-Thomas
Aṣojú ní ilé ìgbìmò Asòfin kékeré
In office
2003–2007
Aṣojú ní ilé ìgbìmò Asòfin kékeré
In office
2007–2011
Aṣojú ní ilé ìgbìmò Asòfin kékeré
In office
29 April 2011 – 29 April 2015
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí20 Oṣù Kínní 1957 (1957-01-20) (ọmọ ọdún 67)
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAPC
OccupationPolitician

Àárò Ayé àti Èkó rè àtúnṣe

Olajumoke jé omo Oloye Molade Okoya-Thomas[2] eni to jé Asoju Oba Eko, a bi ní 20 January 1957. O gba Diploma ní Senior Managers nínú ìmò Government ní yunifásitì Harvard àti àmì-èye diploma nínú ìmò sec. admin láti Burleigh College.[3]

Òsèlú àtúnṣe

Olajumoke Okoya-Thomas wó ipò asoju fun ìgbà keta ní 29 April 2011. Àwon nkan tó nife sí ni riran awon obinrin àti omodé lowo lawujo.[4] O jé alaga teleri fún ìgbìmò tó ún rí sí òrò ewon.[5]

Ni odun 2013, Olajumoke gbero láti se òfin pipa dandan fún àwon obinrin láti fomu fún àwon omo won. A ò padà so igbimo di òfin toriwipe àwon ìgbìmò asojú náà rò pé kò tó láti pon dandan fún àwon obinrin láti fún àwon omo loyan, bi o rile jé wipe wón gbà bé wipe fifun omo loyan.[6] Òun tún ni adari àwon obinrin egbé oselu All Progressive Congress(APC), èka ìpinlè Eko.[7]  

Àwon ìtókasí àtúnṣe

  1. "Public offices held by Olajumoke Abidemi Okoya-Thomas in Nigeria". Citizen Science Nigeria. 2011-05-29. Retrieved 2022-05-30. 
  2. "Jumoke Okoya Runs Into Political Trouble For Eyeing Remi Tinubu's Senatorial Seat! - SocietyNowNg.com ::: News from the Nigerian Society, Entertainment, Movie, Music, Fashion, Parties, Interviews...". societynowng.com. 2014-03-31. Archived from the original on 2014-03-31. Retrieved 2022-05-30.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Olajumoke Okoya-Thomas". Nnu.ng - Nigeria News Update. 2019-03-16. Retrieved 2022-05-30. 
  4. "ShineYourEye". ShineYourEye. Retrieved 2022-05-30. 
  5. "Reps Reject Bill On Exclusive Breast Feeding". Channels Television. 2013-01-29. Retrieved 2022-05-30. 
  6. "Lagos APC: Jumoke Okoya-Thomas task party leaders on Kemi Nelson's conduct". National Daily Newspaper. 2018-09-02. Retrieved 2022-05-30.