Ọlálékan Sàlámì
(Àtúnjúwe láti Olalekan Salami)
Ìdí odó la sìnlú agúnyán;
Ìdí ọlọ la sìnkú ìlọ̀gì;
Níbi a rílẹ̀ sí la sìnkú ọ̀lẹ.
Ìdi igbá la sìnkú asíngbá;
Ìdí gi la sìnkú ìṣọ̀nà,
Níbi a rílẹ̀ sí la sìnkú ọlẹ
Ìdí ẹjọ́ la sìnkú ìbaka;
Níbi a rílẹ̀ sí la sìnkú ọ̀lẹ.
Nígbà tỌ́mọlolú Oníkòyí kú lọ́jọ̀sí;
Ẹ lọ inú yàrá,
Ẹ gbẹ́lẹ̀ ken ìkótó-ikótó;
Ẹ gbẹ́lẹ̀ ken ìkòkò ikòtò
S.M. Raji (2003), Igi Ń dá Lektay Publishers, Ibadan, Oju-ìwé 83-86.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |