Olaniyi Afonja
Olaniyi Mikail Afonja Listen ⓘ (ojoibi 14 October 1974), ti gbogbo eniyan mo si Sanyeri, je omo Naijiria apanilerin, osere ati onise fiimu. [1] [2][3]
Olaniyi Afonja | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Olaniyi Mikail Afonja 14 Oṣù Kẹ̀wá 1974 Oyo State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Orúkọ míràn | Sanyeri |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Durbar Grammar School |
Iṣẹ́ | Oṣere Ori-itage |
Ìgbà iṣẹ́ | 1992- till date |
Olólùfẹ́ | Hawawu Omolara Afonja (m. 2013) |
Àwọn ọmọ | 2 |
Awards | Yoruba Movie Academy awards Best Comedy Actor (Nominated) , 2015 City People Entertainment awards Best Movie Producer of the year and Comic Actor of the year |
Igbesi aye ibẹrẹ ati ẹkọ
àtúnṣeOlaniyi ti won bi ni agbegbe Bola ni ilu Oyo ni ipinle Oyo gege bi omo akoko fun awon obi re, Olaniyi ti ko eko re ni ile-iwe Alakobere St Michael Òkè-èbó, ipinle Oyo ati Durbar Grammar School, ilu Oyo, ipinle Oyo nibi to ti parí eko re. [4]
Iṣẹ
àtúnṣeOdun 1992 ni Obere ise osere Olaniyi, leyin to darapo mo àwọn egbe oni tiata ti ore kan se afihan re. Ni odun 1996, Olaniyi lo si ipinle Eko lati tẹsiwaju ninu ise re, o si ti kopa ninu opolopo fiimu Agbelewo Yorùbá. [4] [5][6]
Filmography
àtúnṣe- Obakeye
- Awero
- Edun Ara
- Jenifa
- Ọpa Kan
- Koboko
- Salako Alagbe
- Omo Iya Meji
- Mama Ṣe O dara
- Osole
- Sanyeri Oloka
- Area Boys
- Ise Awakọ
- Waheed Kolero
- Afoju Meta
Igbesi aye ara ẹni
àtúnṣeOmolara Afonja ni Iyawo Olaniyi àfònjá njẹ ti o si bi omo meji pelu fún pẹlú .[1]
Amin ẹyẹ ati yiyan
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "Comic actor, Sanyeri denies using wedding to raise funds". 13 December 2013. http://www.encomium.ng/comic-actor-sanyeri-denies-using-wedding-to-raise-funds/.
- ↑ http://www.encomium.ng/comic-actor-sanyeri-denies-using-wedding-to-raise-funds/
- ↑ https://punchng.com/anybody-criticising-me-for-making-only-comedy-is-blind-sanyeri/
- ↑ 4.0 4.1 "Sanyeri Olaniyi Afonja". Nigeria Films. http://www.nigeriafilms.com/artists_profile_details.asp?user_id=16553. Retrieved 11 February 2016.
- ↑ "3 funniest Yoruba actors in town". Pulse Nigeria. Archived from the original on 16 June 2017. https://web.archive.org/web/20170616011528/http://www.pulse.ng/movies/sanyeri-okunnu-saka-3-funniest-yoruba-actors-in-town-id3755389.html. Retrieved 11 February 2016.
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2016-05-07. Retrieved 2023-11-08.
Odun | Eye ayeye | Ẹbun | Abajade | Ref |
---|---|---|---|---|
Ọdun 2014 | Ebun Yoruba Movie Academy Awards | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||
Ọdun 2015 | 2015 City People Entertainment Awards | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||
style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [1] |
Wo eleyi na
àtúnṣe- Akojọ ti awọn Yorùbá
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namednobs