Ìwé-alàyé[ìdá]

Olatunji Akinosi Akanni je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. Lọwọlọwọ o n ṣiṣẹ gẹgẹbi Aṣoju ti o nsójú agbègbè Ado-Odo / Ota ti ìpínlè Ogun ni ile ìgbìmò aṣofin àgbà kẹwa. [1] [2] [3]

Awọn itọkasi

àtúnṣe