Olaudah Equiano[2](c. 1745 – 31 osù ke̩ta, o̩dún 1797),[1] jẹ́ ọmọ bíbí Igbo tí wọ́n kó lẹ́rú nígbà okowò ẹrú[3].

Olaudah Equiano
Ọjọ́ìbíc. 1745
Essaka, Benin Empire
Aláìsí31 March 1797 (1797-04-01) (aged 52)[1]
London UK
Orúkọ mírànGustav, Graves
Iṣẹ́Slave, Explorer, Writer, seaman
Gbajúmọ̀ fúnInfluence over British lawmakers to abolish the slave trade; autobiography
Olólùfẹ́Susannah Cullen
Àwọn ọmọJoanna Vassa and Anna Maria Vassa

Igbèsi Ayè Àràkunrin naa

àtúnṣe

Equiano ni a bini Essaka, Eboe ni ilẹ Benin ni ọdun 1745 to si kere julọ ninu awọn ọmọ ti baba rẹ bi. Equiano ni awọn ọga rẹ ninu oko ẹru sọ ni lórukọ lèèmeji, oun jẹ Michael nigba to wa ninu ọkọ óju ọmi ti awọn ẹru to gbè lọ si ilẹ́ america atipè ẹni to ra lẹru lakọkọ sọ ni Jacob[4][5].

Mary Guerin ati aburó rẹ to jẹ mọlẹbi fun ọgà to ra Equiano lẹru kọ ni èdè gẹẹsi. Ni óṣu kejìlá ọdun 1762, pascal ta Equiano lẹru fun Captain James Doran ti Charming Sally ni Gravesend nibi to ti lọ si Caribbean lẹyin naa ni Montserrat ni àwọn erekusu ti Leeward nibi ti wọn ti ta arakunrin naa fun Robert King to jẹ olokowo ni Caribbean ṣugbon to wa lati ilu Philadelphia[6][7].

Ni ọjọ keje, óṣu ke̩rin ọdun 1792, Equiano fẹ Sussanah Cullen ni ilè ijọsin ti St Andrew ni Soham, Cambridgeshire ti wọn si bi ọmọ óbinrin meji; Anna Maria (1793-1797) ati Joanna (1795-1857) ti wọn ṣè iribọ ọmi ni ìjo̩ ti Soham. Iyawó Equiano Susannah ku ni óṣu kejì ọdun 1796 ni ọmọ ọdun mẹrin lèèlọgbọn. Ọmọ óbinrin Equiano agba ku ni ọmọ ọdun mẹrin ni ọdun 1797 ti wọn sin si ìjo̩ ti St Andrew ni Chesterton, Cambridge. Joanna Vassa tọ jẹ ọmọ óbinrin keji ti equiano bi fẹ Henry Bromley ni 1821 ti wọn si awọn mejèèji si itẹ ti Abney Park ni Stoke Newington, London[8].

Equiano ku ni ọjọ kan lèèlọgbọn óṣu ke̩ta ni ọdun 1797 ti wọn si sọ nipa iku rẹ ninu iwè iroyin ti ilẹ british ati AmeriKa. Wọn si arakunrin naa si Whitefield Tabernacle ni ọjọ kẹfa óṣu ke̩rin ọdun 1797[9].

Idanilọla

àtúnṣe

Óṣèrè lọkunrin ilẹ Gambia Louis Mahoney ṣèrè lóri Equiano ninu television ti BBC lori ijagbara ati ominira tita ati rira ẹru ni ọdun 1975[10]. Crater to wa ni Mercury ni a sọ ni "Equiano" ni ọdun 1976[11]. Ni óṣu kankànlá, ọdun 1996 e̩gbé̩ Equiano ni wọn da silẹ ni ilú london lati fi yẹ arakuneim naa si[12].

Equiano ni ṣè afihan rẹ ninu ere agbelewó ti Amazing grace lati ọdọ ólórin ilẹ senegal Youssou N'Dour ni ọdun 2006. Ni óṣu keje, Equiano ni ìjo̩ ti England yẹ si fun ijagbara ninu óminira tita ati rira ẹru[13]. Ni ọdun 2008, ere equiano ni awọn ọmọ ilè iwè ti Edmund waller mọ si Telegraph Hill, lower park ni New cross ni ilú London[14].

Ni ọdun 2022, cambridge yẹ Equiano si pẹlu sisọ afara Riverside si afara Equiano[15][16]. Ni ọdun 2022, ere agbelewó nipa igbesi aye Olaudah Equiano waye lati ọdọ Redio ti BBC[17].

  1. 1.0 1.1 "Olaudah Equiano (c.1745 - 1797)". BBC. 31 Oct 2006. http://www.bbc.co.uk/history/historic_figures/equiano_olaudah.shtml. "Equiano was an African writer whose experiences as a slave prompted him to become involved in the British abolition movement." 
  2. (Olauda Ikwuano correct spelling of name by modern standards) http://emeagwali.com/letters/dear-professor-emeagwali-onye-igbo-ka-nbu.htm
  3. https://cloud.google.com/blog/products/infrastructure/introducing-equiano-a-subsea-cable-from-portugal-to-south-africa
  4. https://www.bbc.co.uk/history/historic_figures/equiano_olaudah.shtml
  5. https://books.google.com.ng/books?id=J8rVeu2go8IC&pg=PA108&redir_esc=y#v=onepage&q&f=false
  6. https://brycchancarey.com/equiano/index.htm
  7. https://web.archive.org/web/20080704140459/http://www.thenation.com/doc/20051121/blackburn/single
  8. https://historicengland.org.uk/listing/the-list/list-entry/1392851
  9. https://web.archive.org/web/20171023230506/http://www.edintone.com/olaudah-equiano/
  10. https://m.imdb.com/title/tt0215412/
  11. https://planetarynames.wr.usgs.gov/Feature/1819
  12. https://brycchancarey.com/equiano/eqs.htm
  13. https://www.churchofengland.org/prayer-and-worship/worship-texts-and-resources/common-worship/churchs-year/calendar
  14. https://brockleycentral.blogspot.com/2008/06/little-treasures-1-equiano.html?m=1
  15. https://www.cambridgeindependent.co.uk/news/city-bridge-to-be-renamed-after-writer-and-abolitionist-olau-9281224/
  16. http://equianobridge.org.uk/
  17. https://www.bbc.co.uk/programmes/m0017kj4