Olawumi Annah Fayemi-Obayelu (ojoibi 20 ère náà 1986) je olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà ati pé o je ọmọ ilé ìgbìmò aṣòfin ìpínlẹ̀ Ondo lọwọlọwọ ti o n sójú Ilaje II, lóri pẹpẹ egbe All Progressives Congress (APC). [1]

Olawumi A. Fayemi-Obayelu
Member of the Ondo State House Of Assembly
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
2023
ConstituencyIlaje II
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí20 Oṣù Kẹta 1986 (1986-03-20) (ọmọ ọdún 38)
Lagos State, Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressives Congress (APC)
Alma materUniversity of Lagos

Awọn itọkasi

àtúnṣe