Olawunmi Banjo
Olawunmi Banjo (tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélógbọ̀n oṣù keje ọdun 1985) jẹ́ olùyàwòrán ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. Ìpínlè Èkó ni ó ń gbé tí ó sì ti ń ya àwórán.
Olawunmi Banjo |
---|
Ayé rè
àtúnṣeA bí Banjo sí ìpínlè Ogun, Nàìjirià, o ka ìwé ní Yunifásitì ti Pan Africa.
Àwọn nǹkan tí ó fi ń yàwòrán ni èèdú àti akiriliki lórí kanfasi. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwòrán rẹ̀ jẹ́ àwòrán alálàyé àti àpèjuwe, àwon ènìyàn sì lè mọ nǹkan tí àwòrán náà túmò sí tàbí tí ó ń gbìyànjú láti sọ láìṣe pé ẹlọ̀mìíràn ṣàlàyé fún won.[1] Ọlawunmi sọ pé àwon nǹkan tó jẹ́ ìwúrí fún òun láti máa yàwòrán ni awọn ohun ìṣẹ́dá lóríṣiriṣi, awon ènìyàn tí o yiká àti sísé akiyesi sí àwon nkan tí ó wà layika rè.[2] Olawunmi jé okan lara omo egbe African Artists Foundation.
Àtòjọ ìṣàfihàn isé rẹ̀
àtúnṣe- 2010 - Organizzato ed esposto alla sezione femminile del Send forth Exhibition per ambasciatore degli Stati Uniti in Nigeria, il Dr. Robin Renee Sanders, presso il Nike Centre for Art and Culture, Lekki a Lagos.
- 2010 - 50 @ 50: Nigerian Women, the Journey so far, Abuja. L'evento è stato organizzato dalla Women for change Initiative.
- 2009 Espone allo Ikoyi Club 1938 nella sezione "Art of Golf" organizzato da A.A.R.C.
- 2009 - Espone al 2 ° Salone Annuale d'Arte "Fyne ArtDiction" Southern Sun Hotel Ikoyi, Lagos.
- 2009 - Espone Championship Cup, Ikoyi Club 1938, Lagos.
- 2009 - Esposto alla Fadan Fashion show, Lagos Civic Center. 2009.
- 2008 - Espone al 17 ° “Nigeria 2008 Art show and Art competition “Nigerian(s) At Work” organizzato dall'African Art Resource Center (AARC). National Museum, Onikan, Lagos. Vincendo il secondo posto
- 2008 - Espone al "The Nigerian Cup" Golf Tournament, Ikoyi Club 1938, Golf Section..
- 2008 -Partecipa alla ” Annual Art Exhibition ITA Foundation “Serendipity” at the Didi Museum. Victoria Island, Lagos.
- 2008 - Partecipa alla 4 ° posto alla Annual All Female Art Exhibition (Wiva Perspective), National Museum, Onikan Lagos. 2008.
- 2008 - partecipa 2 °Annual Art Exhibition “Beyond Imagination” Multimedia foundation of Artists. National Gallery of Art. Aina Onabolu Modern Art, Igamu Lagos.
- 2008 Partecipa al NAIJAZZ 2008 NAIJART Art Exhibition at Studio 868 Bishop Aboyade Cole.
- 2008 - Espone Eden fashion show at Didi Museum. Victoria Island, Lagos.
- 2008 - Espone al primo Art Expo Nigeria at the National Museum, Onikan Lagos.
- 2008 - partecipa a un workshop di graffiti (Lagos on my mind), organizzato e sostenuto dalla African Artists Foundation and British council “WAPI”
- 2008 - Partecipa a un workshop di graffiti alla 54 Raymond Njoku street Ikoyi; - Studio 868 Aboyade Cole; - 10th Lagos Book and Art Festival Exhibition at National Theatre, Iganmu, Lagos.
Àwon Ìtókasí
àtúnṣe- ↑ "Meet Olawunmi Banjo "The Artist"". Bellafricana. 2015-02-05. Retrieved 2022-07-23.
- ↑ Ifechukwu, Chidera (2022-07-23). "Yemisi Shyllon Museum of Art". Yemisi Shyllon Museum of Art. Retrieved 2022-07-23.