Old town of Ghadames
Àdàkọ:Unreferenced Àdàkọ:Infobox UNESCO World Heritage Site Old town of Ghadames (Lárúbáwá: مدينة غدامس القديمة) ni ó jẹ́ ìlú atìjọ́ kan tí wọ́n ń pè ní Ghadames, tí ó wà ní orílẹ̀-èdè Libya tí ó sì jẹ́ ìkan nínú ìlú tí ó wà ní ilẹ̀ aṣálẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Libya tí wọ́n ń pè ní "Jewel of the Desert" wọ́n fi ìlú náà sí abẹ́ UNESCO world heritage ní ọdún 1986.
Ètò ìkọ́lé wọn
àtúnṣeÌlú Ghadames ni ó pín sí ìletò méje tí wọ́n já pọ̀ mọ́ra wọn láti di ìlú ńlá kan. Àwọn ilé tí eọ́n kọ́ náà ni ó bá ìlànà ìkọ́lé ní àwọn ilé aṣálẹ̀ mu látàrí bí ][om]] ṣe wọ́n níbẹ̀. Bí wọ́n ṣe kọ́lé gbe ara wọn wọ̀nyí ni ó mú kí ooru gbígbóná ibẹ̀ ó dínkù.Àdàkọ:Cn