Orílẹ̀-èdè olómìnira

(Àtúnjúwe láti Olominira)

Ijoba Olominira je iru ijoba eyi ti olori orile-ede ki se adobaje, tabi ọba, ti awon eniyan ibe tabi ijoba ti won yan, si je alaselorile lati se akoso orile-ede bi won se fe lai toro ase lowo elomiran. Ni ede Geesi, republic wa la ti res publica ede Latini to tumosi ohun ode tabi ohun igboro.

Àwòrán ìṣètọ́sọ́nà.