Oloye obafemi awolowo
Abí Olóyè Obáfémi Jeremáyà Oyèníyì Awólówò ni ojó kefà, osù keta odun 1909, O si kú ni ojó kesan, osù karun odun 1987 (6 March 1909 – 9 May 1987). O jé òkan nínú àwon ògunna-gbòngbò tí o ja fún òmìnira orílé-èdè Naijeriya. A bíi ni ilu Ìkénné-Rémo, ní ìpínlè Ogun. Òun nï kna ni omo okùnrin ninu gbogbo awon omo bàbá àti iya re bi. Orúko Baba re ni Dafidi Shopolu Awólówò eni ti o yan isé àgbè àti isée agé gedú lááyò àti orúko iya re ni Màríà Efúnyelá Awólówò. Awólówò ni eni akoko ti a mo si Olórí àwon ìran Yorùbá ní gbogbo àgbáyé ti a npe ni Asíwájú Àwon Yorùbá tàbí Asíwájú Omo Oòduà.