Olú Agúnlóyè
(Àtúnjúwe láti Olu Agunloye)
Olu Agunloye ‘Geophysicist’ ni Dr Olú Agúnlóyè ‘ administrator’ sì ni. Wón bí Dr Agúnlóyè ní ojó kerìndínlógún osù késàn-án odún 1948. Wón bí i ní Erusu-Àkókó ní ìpínlè Ondó. Ó kàwé ní University of Ibadan láàrin 1971 sí 1974, Unversity of Reading, U.K ní 1974 àti Massachusetts Institute of Technology. Òun ni Corps Marshall àti Chief Executive, Federal Road Safety Commission télè. Òun sì ni Minister of State for Defence fún àwon Navy télé.
Olú Agúnlóyè |
---|
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |