Olu Falae
Samueli Olúyẹ́misí Fálaè (ojoibi Ojo 21 osu Keesan odun 1938) je oloselu omo ile Naijiria lati Akure ni Ipinle Ondo. Fálaè je Akowe Ijoba Apapo ile Naijiria ati Alakoso Eto Inawo ile Naijiria lati odun 1986 de 1991.
Samueli Olúyẹ́misí Fálaè | |
---|---|
![]() | |
Alakoso Eto Inawo | |
In office 1988–1991 | |
Akowe Ijoba Apapo | |
In office 1986–1988 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Oṣù Kẹ̀sán 21, 1938 Akure, Naijiria |
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |