Olu Oguibe (tí wọ́n bí ní14 October 1964) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America. Ó jẹ́ ayàwòrán àti onímọ̀.[1] Ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ní University of Connecticut, Storrs, ó sì tún jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ àgbà ní Vera List Center for Art and Politics, ní New York City, àti Smithsonian Institution ní Washington, DC.[2]

Olu Oguibe
Olu Oguibe
Ìbí14 Oṣù Kẹ̀wá 1964 (1964-10-14) (ọmọ ọdún 60)
Aba, Eastern Nigeria
PápáConceptual art
Ilé-ẹ̀kọ́University of Connecticut
Ibi ẹ̀kọ́University of Nigeria, Nsukka
School of Oriental and African Studies, University of London
Doctoral advisorJohn Picton
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síState of Connecticut Governor's Arts Award (2013); Arnold Bode Prize (2017)

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Olu Oguibe. Retrieved 29 June 2006.
  2. "Past Smithsonian Institution Fellowship Program Awardees | Smithsonian Fellowships and Internships". www.smithsonianofi.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-01-03. Retrieved 2018-01-02.