Oluchi Mercy Okorie tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlọgbọ̀n osù kẹjọ ọdún 1981 ní Ìlú Èkó jẹ́ agbábọ́ọ̀lù sínú agbọ̀n ti orílẹ̀-ède Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ rí tí ó gbábọ́ọ̀lù fún First Bank BC àti ẹgbẹ́ orílẹ̀-ède Nàìjíríà . Ó ṣe aṣojú Nàìjíríà ní bi 2005, 2006 àti 2007 FIBA Africa Championship .

Oluchi Okorie
No. 7
Iwájú, Àárín
Personal information
Bornọjọ́ kejìdínlọgbọ̀n osù kẹjọ ọdún 1981
Ìlú Èkó, Nàìjíríà
NationalityỌmọ Ilẹ̀ Nàìjíríà
Career information
CollegeTexas State Bobcats

iṣẹ́ Ìdárayá síse àtúnṣe

Láti ogúnjọ́ sí ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n Oṣù kejìlá, ní gbọ̀ngàn eré ìdárayá inú ilé ní Abuja, Nàìjíríà tí wọ́n ti gbàlejò FIBA Africa Championship fún àwọn obìnrin ní ọdún 2005 . Níbi ayeye náà, Oluchi ló sojú orílẹ̀-ède Nàìjíríà tó sì gba ààmì ẹ̀yẹ wúrà.

Ní bi 2006 FIBA Africa Women's Club Champions Cup èyí tí ó kópa, Oluchi gba ààmì ẹ̀yẹ idẹ.

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe