Olufemi Adebanjo (ojoibi June 12, 1961) je oloselu omo orile-ede Naijiria ti o sise gẹ́gẹ́ bi ọmọ ile ìgbìmò asofin ijoba apapo ni ile ìgbìmọ̀ asofin agba orile-ede Naijiria 9th to n soju àgbègbè Alimosho labe egbe oselu All Progressives Congress ki Ayuba Ganiyu Adele lepo. O jẹ Igbakeji Alaga ti Ìgbìmò Ìdàgbàsókè igberiko ni Ile Awọn Aṣoju 9th titi di May 2023. [1]

Olufemi Adebanjo
Political partyAll Progressives Congress (APC)

Awọn itọkasi

àtúnṣe
  1. Empty citation (help)