Olúìlú

(Àtúnjúwe láti Oluilu)

Oluilu je ilu ti ijoba orile-ede kan fi se ibujoko. O tun le tumo si Ilu ti o Ba tobi ju lo, tabi ti o se pataki Ju lo Ni Agbegbe, Orile-Ede, Tabi Ipinle kankan. Fun Apere, Awon Olu Ile ti o se Pataki Julo Ni Aiye Je New York, Ni Orile Ede Amerika, ati London ni orile Ede awon Geesi. Ni Ile Erekusu{Continent} Africa , Ilu Eko Lagos Je Olu Ilu Iwo-Oorun Afrika, Beeni Nairobi ni Orile Ede Kenya ati Addis ababa ni Orile Ede Ityopiya, Je Olu Ile Ni Apa Ila-Oorun, Ni Guusu-Afrika, Ilu Johannesburg ni Orile Ede Guusu Africa Ni Olu Ilu-u Guusa-Afrika, ati Gbogbo Afrilka pelu, Nitori wipe Ilu Johannesbuurg Ni O Ni Idagbasoke ati Itesiwaju Julo Ni Eya Owo sise, Idanilaraya, Asa, Iseda Ohun elo, ati bee bee lo ni Afrika. Ni Ariwa Afrika, Ilu Casablanca ni Orile Ede Morocco, Cairo ni Ijybiti/Egypt, ati Algiers ni Algeria, Je Olu-Ilu ni ona tiwon.

Oluilu