Olukorede Yishau
Olukorede S. Yishau jẹ́ òǹkọ̀wé àti akọ̀ròyìn ọmọ orílẹ̀èdè Nàìjíríà . Ó ti ṣe atokọ pípẹ́ fún ẹ̀bùn 2021 Nà̀ij̀iríà fún Litiréṣọ̀ .
Olukorede Yishau | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 27 Oṣù Kẹfà 1978 Somolu, Lagos, Lagos State |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Ambrose Alli University |
Iṣẹ́ | Journalist Author Editor |
Ìgbà iṣẹ́ | 2006–present |
Notable work |
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé re àti iṣẹ́
àtúnṣeA bí Yishau ni Ṣomolu, ní ̀ipínlẹ̀ Èkó . Ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìbánisọ̀rọ̀ púpọ̀ ní Ambrose Alli University, Ekpoma . Ó ti ṣiṣẹ́ bí oníṣẹ́ ìròyìn ní Orísun, Sọ Ìwé ìròhìn àti pé ó jẹ́ Olóòtú Alábàáṣepọ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́ ní Ìwé ìròhìn Nation .
Ìwé àkosílẹ̀
àtúnṣe- Yishau, Olukorede (2018). In The Name Of Our Father. Nigeria: Parresia Publishers.[1]
- Yishau, Olukorede (2020). Vaults of Secrets. Nigeria: Parresia Publishers.