Olumide Oworu

Olumide Oworu (bíi ní, Ọjọ́ ọ̀kànlélógún Oṣù kejìlá Ọdún 1994) jẹ́ òṣèré, awosẹ̀ àti olórin ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1][2][3]

Olivier Oworu
Ọjọ́ìbíOṣù Kejìlá 21, 1994 (1994-12-21) (ọmọ ọdún 28)
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Actor, model, rapper
Ìgbà iṣẹ́2000–present

Iṣẹ́Àtúnṣe

Olumide kàwé ní King's College, Lagos àti University of Lagos.[4] Ó tún jẹ́ akẹ́kọ́ ní Babcock University. Olumide bẹ̀rẹ̀ eŕ ṣíṣe ní ọmọ ọdún mẹ́fà pèlú amóhùn máwòran ti ọ̀sẹ̀ẹ̀sẹ̀, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Everyday People. Wọ́n tún mòọ́ sí ipa 'Tari' tí ó kó ní ‘The Johnsons’. Ó tún kópa nínú àwọn eré míràn bíi The Patriot, The Men In Her Life, Hammer, Stolen Waters and New Son.[5] Olumide hùwà  ‘Weki’ ní Mtv Base's Shuga , abala kẹta àti ìkẹrin.[6][7][8][9]

Àwọn eré tí ó ti kópaÀtúnṣe

  • Everyday people
  • A Soldier's Story
  • Shuga
  • 8 Bars and a clef
  • The Johnson's
  • The Patriot
  • Staying strong
  • Hammer

Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe