Olusegun Olutoyin Aganga
Olóṣèlú
Olusegun Olutoyin Aganga (ti a bi ni odun 1955) je Minisita fun Iṣẹ, Iṣowo ati idoko ti Najiriya[1].
Olusegun Olutoyin Aganga | |
---|---|
Federal Minister of Industry, Trade and Investment Nigeria | |
In office 9 March 2013 – 29 May 2015 | |
Federal Minister of Trade and Investment Nigeria | |
In office 11 July 2011 – 9 March 2013 | |
Federal Minister of Finance Nigeria | |
In office 6 April 2010 – June 2011 | |
Asíwájú | Mansur Mukhtar |
Arọ́pò | Ngozi Okonjo-Iweala |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 1955 Lagos State, Nigeria |
Aganga ti ni iyawo to oje Abiodun Aganga (née Awobokun). O ni awọn ọmọ mẹrin. Oun tun jẹ anor si Gomina ti iṣaaju ti Kwara State Salaudeen Latinwo .