Oluwakemi Adejoro Ojo
Oluwakemi Adejoro Ojo Listen, tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí Kemi Korede, jẹ́ òṣèrébìnrin, àti olóòtú ètò orí tẹlifíṣọ́ọ̀nù, bẹ́ẹ̀ sì ni ó jẹ́ aṣagbátẹrù ayẹyẹ. Wọ́n máa ń ṣàfihàn rẹ̀ nínú àwọn fíìmù Yorùbá.[1][2][3][4] Oluwakemi àti Toyin Alausa ni wọ́n jọ tẹwọ́bọ̀wé fún Honeyglow skin care ní ọdún 2021, ẹni tó ni ilé-iṣé náà ló ṣètò èyí.[5]
Oluwakemi Adejoro Ojo | |
---|---|
Orúkọ míràn | Kemi Korede |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Iṣẹ́ | Film actress, TV presenter, Producer |
Ìgbà iṣẹ́ | 2006- till present |
Àwọn ọmọ | 3 |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeFún ẹ̀kọ́ ilé-ìwé gíga, ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa iṣé nọ́ọ̀sì.[6]
Iṣẹ́ tó yàn láàyò
àtúnṣeKemi Korede bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré-ṣíṣe láti ìgbà tó wà ní ilé-ìwé girama, àmọ́ ó bọ́ sí gbàgede ní ọdún 2006, tó sì kópa nínú fíìmù Omobewaji[7]
Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀
àtúnṣeÌgbésí ayé rẹ̀
àtúnṣeKemi ti lọ́kọ, ó sì ti bímọ mẹ́ta.[10]
Àwọn ìtókasí
àtúnṣe- ↑ "Adunni Ade: People make me nervous". The Nation Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-05-07. Retrieved 2022-08-02.
- ↑ "Kemi Korede To Funke Akindele: You're A Woman of substance". Independent Newspaper Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-02-16. Retrieved 2022-08-02.
- ↑ "You're a rare gem, actress Kemi Korede praises Funke Akindele". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-02-16. Retrieved 2022-08-02.
- ↑ "Why I sometimes feel like quitting acting — Ife Olawale". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-02-23. Retrieved 2022-08-02.
- ↑ Online, Tribune (2021-08-02). "Toyin Alausa, Jide Awobona, Kemi Korede, others join Honeyglow family". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-02.
- ↑ Kehinde, Seye (2018-10-01). "Why I Left My Nursing Career For Acting – Pretty Actress, KEMI KOREDE Tells City People". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-02.
- ↑ Online, Tribune (2019-02-09). "With N500m, you can tame me —Actress, Nkechi Blessing Sunday". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-02.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:12
- ↑ Kaduna, George (2021-12-12). "INTERVIEW: Instagram critics strengthening my relationship with my husband - Blessing Nkechi". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-02.
- ↑ Online, Tribune (2020-07-26). "Femi Adebayo, Fathia, others honour Kemi Korede". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-02.