Dr. Oluyombo Adetilewa Awojobi ( láti March 1, 1951 sí April 17, 2015) jẹ́ oníṣẹ́-abẹ ìgbèríko ní orílẹ́-èdè Nàìjíríà (Nigeria), Óníṣẹ́-ìwádìí, Olùpilẹ̀sẹ̀ àti Ọmọnìyàn. Ó jẹ́ olókìkí jùlọ fún àwọn iṣẹ́ tí ó ti ṣe ní ilé ìwòsàn Adejobi (Awojobi Clinic) tó wà ní Eruwa (ACE) ní agbègbè ìjọba ìlà-oòrùn Ibarapa ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ (Oyo State).[1]

Oluyombo Awojobi
Fáìlì:Oluyombo Awojobi.png
Ọjọ́ìbíMarch 1, 1951
AláìsíApril 17, 2015 (Aged 64)
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Ibadan
Gbajúmọ̀ fúnRural Surgery
Awojobi Clinic Eruwa
Olólùfẹ́Tinu Awojobi
Àwọn olùbátanAbiola Arowojolu & Folake Ozoro (Sisters); Yinka Awojobi, Ayodele Awojobi & Busola Awojobi (Brothers)

Ó jẹ́ aṣáájú-ọ̀nà ìdàgbàsókè àgbègbè àti ìṣelọ́pọ̀ ti ìmọ̀tuntun, àwọn ẹ̀rọ ìṣòògùn tí ó yẹ.[2]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

Ó jẹ́ ọmọ Oloye Daniel Adekoya Awojobi, ẹni tí ó jẹ́ ọ̀gá ibùdókọ̀ ti Àjọ tó ń rí sí ètò ìrìnnà ojú irin ti Nàìjíríà (Nigerian Railway Corporation) ẹni tí wọ́n tọ́ dàgbà ní agbègbè Ikorodu ní Ìpínlẹ̀ Èkó (Lagos State) pẹ̀lú Ìyá wa Comfort Bamidele Awojobi (née Adetunji), oníṣòwò kékeré tí wọ́n tọ́ dàgbà ní agbègbè Modakeke, Ile-Ife, ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun (Osun State) ní March 1951.[3] Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ CMS Grammar school láàrin ọdún 1963 sí ọdún 1969. Ó lọ kẹ́kọ̀ọ́ nípa Ìṣègùn Òyìnbó àti iṣẹ́ abẹ (Medicine and Surgery) ní College of Medicine, University of Ibadan níbi tó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ìjìnlẹ̀ nínú Iṣẹ́ abẹ ní ọdún graduated 1975[1] Ó gba àmì-ẹ̀yẹ Adeola Odutola gẹ́gẹ́ bíi akẹ́kọ̀ọ́ onímọ̀ ìṣègùn tí ó dára jùlọ ní àkókò ìkẹ́kọ̀ọ́ jáde rẹ̀.[4]

Ètò ẹ̀kọ́

àtúnṣe

Awojobi (Dr.) bẹ̀rẹ̀ ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé ẹ̀kọ́ṣẹ́ mọṣẹ́ ìwòsàn ti ifásitì ti Ìbàdàn (University College hospital, Ibadan ) gẹ́gẹ́ bíi olùgbé oníṣẹ́-abẹ (surgical resident) láàárín ọdún 1977 sí ọdún 1983. Ó lọ ṣe iṣẹ́ ìwòsàn ìgbèríko ní Ilé ìwòsàn agbègbè tó ń bẹ ní Eruwa ní August 25, 1983.[5] Ó kọ̀wé fiṣẹ́ sílẹ̀, ó sì dá ilé-ìwòsàn Awojobi sílẹ̀ èyí tó ń bẹ ní Eruwa - Awojobi Clinic, Eruwa (ACE), ní October 27, 1986 níbi tí ó ti ṣiṣẹ́ títí tí ọlọ́jọ́ fi dé.[6][7]

Wọ́n mọ̀ ọ́n fún aṣáájú-ọ̀nà ìdàgbàsókè ti ìṣelọ́pọ̀ agbègbè ti awọn ẹ̀rọ ìṣòògùn tí ó yẹ.[2] Àwọn ohun èlò tí wọ́n ń lò ní ilé ìwòsàn Awojobi (Awojobi Clinic) gẹ́gẹ́ bíi (operating table, autoclave, water distiller, pedal suction pump and haematocrit centrifuge) jẹ́ èyí tí ó ṣẹ̀dá láti ọwọ́ ara rẹ̀.[8] Ó tún ṣe àwọn omi inú iṣan àti àwọn aṣọ tó wà fún iṣẹ abẹ lábẹ́lé.

Wọ́n kà á mọ́ ara àwọn oníṣẹ́ ìwòsàn tó ní àbójútó ní àjọ onímọ̀ ìṣègùn ní àgbáyé (World Medical Association) ní 2005.[9]

Ó gbé iṣẹ́ ìṣègùn Hernia kalẹ̀ [10] ní ilé-ìwòsàn Awojobi ní ọdú 2013, níbi tí wọ́n ti ṣe iṣẹ́ abẹ fún àwọn ènìyàn tí wọ́n tó 70 níye pẹ̀lú àrùn inguinoscrotal hernias fún odidi ọjọ́ mẹ́fà gbáko.[11]

Sáájú kó tó kú, ó ṣe àgbékalẹ̀ ibùdó tí wọ́n ti ń tọ́jú àìsàn jẹjẹrẹ (Olajide Ajayi Cancer Centre).[1]

Ètò ayé rẹ̀

àtúnṣe

Ó fẹ́ Tinu Awojobi, ẹni tí ó jẹ́ (radiographer) wọ́n sì bí àwọn ọmọ méjì, Yombo àti Ayodele.[1]

Àwọn ogún rẹ̀ (Legacy)

àtúnṣe

The Dr Oluyombo Adetilewa Awojobi's Prize for Best Graduating Student in Biomedical Engineering at The Bells University, Ota was endowed in his honour.[12]

A documentary about his life titled 'An Uncommon Service: A tribute to Dr. Awojobi' was screened at the iREP monthly documentary film screening series at Freedom Park, Lagos.[13]

Àwọn ìwé tí ó tẹ̀ jáde

àtúnṣe
  • Modified pile suture in the outpatient treatment of haemorrhoids - Oluyombo A Awojobi, 1983[14]
  • Abdominal incisional hernia in Ibadan - Oluyombo A Awojobi, S O Itayemi, 1983[15]
  • Use of Foley catheter in suprapubic punch cystostomy: An adaptation - Oluyombo A Awojobi, 1983[16]
  • Paediatric inguinoscrotal surgery in a district hospital- Oluyombo A Awojobi, J K Ladipo, A C Sagua, 1988[17]
  • Sutureless circumcision - Oluyombo A Awojobi, 1992[18]
  • The hospital water still - Oluyombo A Awojobi, 1993[19]
  • Principles of rural surgical practice - Oluyombo A Awojobi, 1998
  • The manual haematocrit centrifuge - Oluyombo A Awojobi, 2002[20]
  • A review of surgical cases and procedures in rural Nigeria - Oluyombo A Awojobi, 2002[21]
  • Epidural needle and intraosseous access - Oluyombo A Awojobi, 2003[22]
  • 20 years of primary care surgery in Ibarapa - Oluyombo A Awojobi, 2004[23]
  • Inguinal hernia in Nigeria - Oluyombo A Awojobi, AA Ayatunde 2004[24]
  • Spontaneous appendicocutaneous fistula: A case report - O M Tokode, Oluyombo A Awojobi, 2004[25]
  • Surgical training in Nigeria: a reappraisal - Oluyombo A Awojobi, 2005[26]
  • The travails of rural surgery in Nigeria and the triumph of pragmatism - Oluyombo A Awojobi, 2005[27]
  • Atraumatic sutures can be made locally - Oluyombo A Awojobi, 2005[28]
  • Engineering fabrication in the rural Nigerian medical practice - Oluyombo A Awojobi, 2007[29]
  • Rising to the challenge of rural surgery - Oluyombo A Awojobi, 2010[4]
  • Rural based medical practice in Nigeria - The Ibarapa Experience - Oluyombo A Awojobi, 2011[30]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 "Awojobi: Life of uncommon service". Latest Nigeria News, Nigerian Newspapers, Politics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-05-14. Retrieved 2021-02-04. 
  2. 2.0 2.1 WHO. Towards improving access to medical devices through local production. Phase II Report of a case study in four sub-Saharan countries. https://apps.who.int/iris/bitstream/handle/10665/206545/9789241510141_eng.pdf. 
  3. "CyberschuulShout : A File on Excellence, Service, and Patriotism". 2009-05-03. Archived from the original on 2009-05-03. Retrieved 2021-02-04. 
  4. 4.0 4.1 Les, Olson (2010-05-01). "Rising to the challenge of rural surgery". Bulletin of the World Health Organization 88 (5): 331–332. doi:10.2471/blt.10.040510. ISSN 0042-9686. PMC 2865669. PMID 20461212. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=2865669. 
  5. "Homepage". The Nation Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-08. 
  6. "Farewell, Yombo Awojobi". Retrieved 2021-02-04 – via PressReader. 
  7. Lala, Emmanuel (2015-08-16). "Meet Top 14 Nigerian Innovators To Watch Out For | 36NG" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-04-01. 
  8. Soman, Dilip; Stein, Janice Gross; Wong, Joseph (2014-01-22) (in en). Innovating for the Global South: Towards an Inclusive Innovation Agenda. University of Toronto Press. ISBN 978-1-4426-6648-1. https://books.google.com/books?id=20CWAwAAQBAJ&q=oluyombo+awojobi&pg=PA60. 
  9. "SPLA | Yombo Awojobi". Spla (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-02-04. 
  10. "Operation Hernia – Operation Hernia (OH) is an independent charity providing opportunities for clinicians repairing hernias in the developing world." (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-02-04. 
  11. "Eruwa – Operation Hernia" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-02-04. 
  12. "I hate reading – The Bells best graduating student". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-02-04. 
  13. "Dr Awojobi | Documentary Tribute | ASIRI". ASIRI Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-06-16. Archived from the original on 8 November 2023. Retrieved 2021-02-04. 
  14. Awojobi, O. A. (1983). "Modified pile suture in the outpatient treatment of hemorrhoids" (in en-US). Diseases of the Colon & Rectum 26 (2): 95–7. doi:10.1007/BF02562582. PMID 6337036. https://dx.doi.org/10.1007%2FBF02562582. 
  15. Awojobi, Oluyombo A.; Itayemi, S. O. (2016-06-25). "Abdominal Incisional Hernia in Ibadan" (in en). Tropical Doctor 13 (3): 112–114. doi:10.1177/004947558301300306. PMID 6879690. https://journals.sagepub.com/doi/10.1177/004947558301300306. 
  16. Awojobi, Oluyombo A. (2016-06-25). "Use of Foley Catheter in Suprapubic Punch Cystostomy: An Adaptation" (in en). Tropical Doctor 13 (4): 189. doi:10.1177/004947558301300418. PMID 6649046. https://journals.sagepub.com/doi/10.1177/004947558301300418. 
  17. Awojobi, Oluyombo A.; Ladipo, J. K.; Sagua, A. C. (2016-06-25). "Paediatric Inguinoscrotal Surgery in a District Hospital" (in en). Tropical Doctor 18 (1): 23–24. doi:10.1177/004947558801800109. PMID 3341085. https://journals.sagepub.com/doi/10.1177/004947558801800109. 
  18. Awojobi, Oluyombo A. (2016-06-25), "Sutureless Circumcision", Tropical Doctor (letter) (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), 22 (3): 124, PMID 1641891, doi:10.1177/004947559202200318, retrieved 2021-02-05  Unknown parameter |s2cid= ignored (help)
  19. Awojobi, Oluyombo A. (2016-06-25). "The Hospital Water Still" (in en). Tropical Doctor 23 (4): 173–174. doi:10.1177/004947559302300413. PMID 8273164. https://journals.sagepub.com/doi/10.1177/004947559302300413. 
  20. Awojobi, Oluyombo A. (2016-06-25). "The Manual Haematocrit Centrifuge" (in en). Tropical Doctor 32 (3): 168. doi:10.1177/004947550203200318. PMID 12139162. https://journals.sagepub.com/doi/10.1177/004947550203200318. 
  21. Awojobi, Oluyombo A. (2002). "A review of surgical cases and procedures in rural Nigeria" (in en). Archives of Ibadan Medicine 3 (2): 65–68. doi:10.4314/aim.v3i2.34587. ISSN 1467-6958. https://www.ajol.info/index.php/aim/article/view/34587. 
  22. Awojobi, Oluyombo A. (2016-06-25), "Epidural Needle and Intraosseous Access", Tropical Doctor (letter) (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), 33 (1): 59, PMID 12568533, doi:10.1177/004947550303300131, retrieved 2021-02-05  Unknown parameter |s2cid= ignored (help)
  23. Awojobi, Oluyombo A. (2003). "Twenty Years of Primary Care Surgery in Ibarapa" (in en). Nigerian Journal of Ophthalmology 11 (2): 49–53. doi:10.4314/njo.v11i2.11928. ISSN 2468-8363. https://www.ajol.info/index.php/njo/article/view/11928. 
  24. Awojobi, O. A.; Ayantunde, A. A. (2016-06-25). "Inguinal Hernia in Nigeria" (in en). Tropical Doctor 34 (3): 180–181. doi:10.1177/004947550403400322. PMID 15267057. https://journals.sagepub.com/doi/10.1177/004947550403400322. 
  25. "Spontaneous Appendicocutaneous fistula: A case report". Annals of Ibadan Postgraduate Medicine 2: 48–50. https://www.ajol.info/index.php/aipm/article/download/39093/26215. 
  26. Awojobi, Oluyombo A. (2005-12-13). "Surgical training in Nigeria: a reappraisal" (in en). Archives of Ibadan Medicine 6 (2): 59–61. doi:10.4314/aim.v6i2.34629. ISSN 1467-6958. https://www.ajol.info/index.php/aim/article/view/34629. 
  27. Awojobi, O. (2005) (in en). THE TRAVAILS OF RURAL SURGERY IN NIGERIA AND THE TRIUMPH OF PRAGMATISM. 
  28. Awojobi, Oluyombo A. (2016-06-25). "Atraumatic sutures can be made locally" (in en). Tropical Doctor 35 (2): 124. doi:10.1258/0049475054036805. ISSN 0049-4755. PMID 15970054. https://journals.sagepub.com/doi/10.1258/0049475054036805. 
  29. "Engineering Fabrication in Nigerian rural medical practice - The Eruwa experience". LAUTECH Journal of Engineering and Technology 4: 58–62. Archived from the original on 8 November 2023. https://web.archive.org/web/20231108162546/https://www.laujet.com/index.php/laujet/article/download/193/164. Retrieved 8 November 2023. 
  30. "here - International Federation of Rural Surgery". studylib.net (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-02-04.