Omi Àgbọn
Omi Àgbọn ni omi tí ó mọ́ kangá tí a má ń rí nínú àgboṇ tí ó bá ti gbó dára dára. Bí agbọn ṣe ń gbó sí ni ẹran inú àgbọn ma ń yíra padà sí. Omi àgbọn yàtọ̀ sí wàrà (milk) àgbọ́n. Wàrà àgbọn ni wọ́n ma ń rí láti ara rírẹ́ tàbí híha tinú àgbọn pọ̀ mọ́ra wọn tí wọ́n sì fún kí omi inú rẹ̀ ó lè jáde.[1]
Ìwúlò Omi Àgbọn
àtúnṣeOmi àgbọn lè ṣeé lò gẹ́gẹ́ bí ohun mímu ìgbafẹ́ ẹlẹ́riùdòdò, ṣíṣe ìwòsàn fún ìgbẹ́ gbuuru, tàbí fífúni lókun lẹ́yìn eré ìdárayá. Pàá pàá jùlọ, ó tún wúlò fún ìtọ́jú àìsàn ẹ̀jẹ̀ ríru àti láti mú ̣ara le kalẹ̀ fún eré ìdárayá. [1] [2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "Coconut Water: Uses, Side Effects, Interactions, Dosage, and Warning". WebMD. 2019-01-30. Retrieved 2019-12-06.
- ↑ "8 Science-Based Health Benefits of Coconut Water". Healthline. 2018-09-06. Retrieved 2019-12-06.