Omo-Love Branch (tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹwàá, oṣù kìíní ọdún 1974) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá bìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó máa ń gbá bọ́ọ̀lù ní àyè àbò-ilé fún ọkọ̀ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Nigeria. Ó wà lára ikọ̀ àkọ́kọ́ àwọn obìnrin tí wọ́n ṣojú Nàìjíríà nínú ìdíje 1991 FIFA Women's World Cup àti 1995 FIFA Women's World Cup.[1]

Omo-Love Branch
Personal information
Ọjọ́ ìbí10 Oṣù Kínní 1974 (1974-01-10) (ọmọ ọdún 50)
Playing positionDefender
National team
Nigeria
† Appearances (Goals).
‡ National team caps and goals correct as of 5 June 1995 (before the 1995 FIFA Women's World Cup)

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "FIFA Women's World Cup Sweden 1995 - Teams". FIFA Women's World Cup Sweden 1995. FIFA. 1995. Archived from the original on 2 July 2015. Retrieved 2007-09-28.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)