Omo-Oba Adereti Sijuade

Ọmọ-Ọba Adéretí Ṣíjúwadé (1895 - 11 May 1945) jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹbí Síjúwadé àti ọlọ́rọ̀ olówò kòkó. Òun sì ni ọmọ Ọọ̀ni Adelekan Olubuse I tó jẹ́ Ọọ̀ni Ilé-Ifẹ̀ ẹlẹ́ẹ̀kẹrìndínláàádọ́ta àti bàbá Oba Okunade Sijuwade (Olubuse II) tó jẹ́ Ọọ̀ni àádọ́ta ti Ilé-Ifẹ̀.[1][2]

Ọmọ-Ọba Adérétí Ṣíjúwadé ní okòwò tó ń gbèrú ní agbègbè Ìjú, Alagbado àti Abeokuta, ní ìpínlẹ̀ Ògùn.[3]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Nigeria, Guardian (2015-09-03). "Rare gems: Ooni Aderemi and Sijuwade". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2023-06-29. Retrieved 2023-07-03. 
  2. "Ooni Sijuwade's Business Side -". The NEWS (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-08-09. Retrieved 2023-07-03. 
  3. https://allafrica.com/stories/201508181129.html