Omotayo Akinremi (tí wọ́n bí ní 13 September 1974) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-edè Nàìjíríà tó máa ń kópa nínú ìdíje eré-sísá. Ó kópa nínú ìdíje àárín orílẹ̀-èdè àti ní àgbáyé, tó ṣojú Nàìjíríà. Ó gbé ipò kìíní, tó sì mu gba àmì-ẹ̀yẹ wúrà nínú ìdíje1992 àti 1993 African Championships in Athletics ní eré sísá onírinwó mítà. Bákan náà ni ó gba àmì-ẹ̀yẹ onídẹ ní ìdíje ti ọdún 1990 àti ní àsìkò 1991 All-Africa Games, níbi tí ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ onídẹ nínú ìdíje irinwó mítà. Síwájú si, ó kópa nínú ìdíje ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fún 4 × 400 m relay team, tó sì gba àmì-ẹ̀yẹ onídẹ nínú ìdíje 1993 Summer Universiade pẹ̀lú Olabisi Afolabi, Omolade Akinremi àti Onyinye Chikezie.[1][2]
Omotayo AkinremiÒrọ̀ ẹni |
---|
Orúkọ àbísọ | Omotayo Akinremi |
---|
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
---|
Ọjọ́ìbí | 13 Oṣù Kẹ̀sán 1974 (1974-09-13) (ọmọ ọdún 50) |
---|
Iṣẹ́ | sprinter and hurdler |
---|
Sport |
---|
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
---|
|
---|
Àwọn ìdíje ti ilẹ̀ Africa
àtúnṣe
- 400 metres hurdles – 57.59 s (1992)
- 400 metres – 52.53 s (1993)