Omotayo Aramide Oduntan (tí a bí ní ọjọ́ Kàrún oṣù kẹfà ọdún 1957), jé olósèlú ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó ń se asojú ekun Alimosho II ní house Assembly ìpinlè Èkó, o jé omo egbé oselu All Progressive Congress(APC).[1]

Lateefat Okunnu
Ọjọ́ìbíLateefat Okunnu
3 Oṣù Kejìlá 1939 (1939-12-03) (ọmọ ọdún 84)
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Civil servant
Gbajúmọ̀ fúnGómìnà ìpínlè Èkó

Ayé rè àti isé rè àtúnṣe

A bi Omotayo Oduntan ní Ìpinlè Èkó, orílè-èdè Nàìjíríà, nibi tí o ti pari ìwé primari àti Sekodiri rè. O gba àmì-èye ninú ìmò food hygiene àti food handling ní ilé-ìwé Royal Institute of public Health. O lo sáà gégé bí asjou Alimosho II ni house assembly ti ìpínlè Èkó.

Ìdílé rè àtúnṣe

Omotayo ní igbeyawo rè àkókó(pèlú Ojogbon Ore Yusuf) tuka léyìn odun merin, o sì ni oun lo sokunfa idi tí igbeyawo náà fi tuka. Bí o tile jé wipe o se igbeyawo ní omokekere(nigba tí o je omo odun mokandinlogun), igbeyawo won ni omo meta laarin odun merin., èyí ti ìkan ninú won padà fi ayé sílè. O pada fé Reverend Bola Oyeledun. eni tí o jé ojise Olorun.[2]

Àwon ìtókasí àtúnṣe

  1. "Omotayo Oduntan". DBpedia. 1957-06-05. Retrieved 2022-05-30. 
  2. "'My life at 60' – Hon. Omotayo Oduntan Oyeledun". Encomium Magazine. 2017-06-05. Retrieved 2022-05-30.