Omotunde Adebowale
Omotunde Adebowale David tí orúkọ inagi rẹ jẹ Lolo 1 je Òṣeré àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni ìpínlè Nàìjíríà. Òun sì ní atọkun ètò Oga Madam lórí Wazobia Fm 94.1.[1]
Omotunde Adebowale David | |
---|---|
Iṣẹ́ | Actress, Radio presenter |
Àwọn ọmọ | 4 |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeOmotunde lọ sí ilé ẹ̀kọ́ tí Ijebu-Ode Anglican Girls Secondary School.[2] Ó kà ìwé imọ òfin ni ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Lagos State University.
Ìṣe
àtúnṣeỌmọtunde bẹere ìṣe gẹ́gẹ́ bí agbejoro ni ọdún 2000. Ó ṣíṣe ni ilẹ̀ ìṣe òfin títí di ọdún 2004 tí ó wà padà wá dì agbóhùnsáfẹ́fẹ́.[3] [4]
Omotunde má ń kópa nínú eré fíìmù ṣíṣe pàápàá ti èdè òyìnbó àti Yorùbá.[5][6]
Ó kópa nínú eré Jenifa's Diary, ní ibi tí ó ti ṣe Adaku.
Ó kọ́kọ́ sọ̀rọ̀ lórí afẹ́fẹ́ gẹgẹ bí agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ní ìgbà tó dára pọ̀ mo Metro Fm. Ó padà wá dára pọ̀ mọ́ Wazobia Fm kí ó tó kúrò ní ọdún 2019 lẹ́yìn tí ó ti ló kọjá ọdún mọkànlá pelu wọn.[7] [8][9]
Omotunde ṣe ère àkọ́kọ́ títí ẹ jáde ní ọdún 2020, èyí tí ó pè àkọ́ri rẹ ni When Love is not Enough. Okiki Afolayan ni ó dárí ère na.[10] [11] [12]
Ó gbà orúkọ inagi rẹ ní ori ètò kàn nínú ètò kan tí ó ti ń ṣe atọkun. Ó sọ fún àwọn ẹ̀yán kí wọn fún òun ní orúkọ inagi, nínú orúkọ tí àwọn èèyàn fún, nibẹ ní o ti wa mú Lolo 1.[13]
Ní oṣù keje ọdún 2017, La Mode magazine fi ṣe ojú ìwé àkọ́kọ́ wọn.[14]
Ẹ̀ya Ara Ìwé Ìròhìn
àtúnṣeÌwé ìròhìn La Mode tí ó kẹhìn jẹ́ ikọja pẹ̀lú Chika Ike, ṣùgbọ́n ọ̀ran lọ́wọ́lọ́wọ́ yìí pàápàá gbóná! Ọ̀rọ̀ tuntun yìí jẹ́ gbogbo nípa ẹwà, agbára, àti àwọn ìgun àti àwọn ẹ̀yà ara ẹ̀rọ̀ ìṣòwò njagun Temi Aboderin-Alao àti ènìyàn rédíò Omotunde Adebowale David tí a ń pè ní Lolo1.
Ẹ̀bùn
àtúnṣeỌmọtunde gba Ẹ̀bùn agbóhùnsáfẹ́fẹ́ tó táyọ̀ jùlọ ní Ẹ̀kọ́ láti ọwọ́ Nigerian Broadcasters Merit Awards.[15]
Ayé rẹ̀
àtúnṣeỌmọtunde jẹ́ ìyá ọmọ mẹ́rin, ọkùnrin mẹ́ta àti obìnrin kan. Kò sí pẹ̀lú ọkọ rẹ̀ mọ́.[16][17][18]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Bankole, Ibukun Josephine (18 October 2017). "Adaku: OAP Lolo1 condemns the quality of Nigerian music". Naija News.
- ↑ "Lolo 1: I Have Three Sons, One Daughter But I Am Single - THISDAYLIVE" (in en-US). THISDAYLIVE. 2016-10-29. https://www.thisdaylive.com/index.php/2016/10/29/lolo-1-i-have-three-sons-one-daughter-but-i-am-single/.
- ↑ "My mum cried when I dumped law for entertainment, says Lolo 1". Punch Newspapers.
- ↑ "Ẹda pamosi". guardian.ng. Archived from the original on 2021-10-30. Retrieved 2020-05-02.
- ↑ "I’m not bothered about hate comments on my picture –Lolo". Punch Newspapers.
- ↑ "Omotunde Adebowale David". IMDb.
- ↑ "Lolo exits Wazobia FM - P.M. News". www.pmnewsnigeria.com.
- ↑ "Lolo exits Wazobia FM - P.M. News". www.pmnewsnigeria.com.
- ↑ "Wazobia FM celebrates Lolo 1 & bids her farewell after a Decade of Worthy Service". BellaNaija. 17 July 2019.
- ↑ "Lolo 1 produces new movie “When Love is Not Enough“ - P.M. News". www.pmnewsnigeria.com.
- ↑ Tv, Bn (30 January 2020). "Lolo 1 makes Productional Debut with the Film “When Love is Not Enough” | WATCH the Trailer". BellaNaija.
- ↑ "Lolo 1 Produces 1st Movie 'When Love Is Not Enough'". aljazirahnews. 6 February 2020. Archived from the original on 7 February 2021. Retrieved 2 May 2020.
- ↑ Afolabi, Deborah (19 May 2018). "Omotunde Adebowale: Why I dumped law for acting". Daily Trust.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Beauty, Strength & Curves! Temi Aboderin-Alao & Lolo1 are the cover stars for La Mode Magazine’s July Issue". BellaNaija. 1 July 2017.
- ↑ Nbmawards.com. "Nigerian Broadcasters Merit Awards". nbmawards.com. Archived from the original on 2018-11-03. Retrieved 2018-11-03.
- ↑ "Life as a single mother of four –Omotunde David (Lolo 1), broadcaster". The Sun Nigeria. 26 October 2019.
- ↑ "Being single mum my biggest challenge –Lolo 1, OAP". The Sun Nigeria. 5 February 2017.
- ↑ "Lolo 1 of Wazobai FM - My Next Husband Should Be an Igbo Man". Nigerian Bulletin - Top Nigeria News Links.