Oníṣe:Mukandas Zainab/Alton R. Waldon, Jr.
- Mukandas Zainab/Alton R. Waldon, Jr. at the Biographical Directory of the United States Congresshttps://en.wikipedia.org/wiki/Biographical_Directory_of_the_United_States_Congress
Alton Ronald Waldon Jr. (December 21, 1936 – June 9, 2023) jẹ́ olóṣèlú ìlú Amẹ́ríkà àti adájọ́ láti New York tí ó ṣiṣẹ́ ní Ilé Àṣòfin ti United States láti 1986 sí 1987 ní àfikún sí stints ní New York state Assembly 1983 si 1986 ati New York State Senate láti 1991 si 2000, gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ ti Democratic Party .
Ìbẹ̀rẹ̀ Ìgbésí ayé àti ẹ̀kọ́
àtúnṣeTí a bí ní Lakeland, Florida, Waldon gboyè jáde ní Boys High School ní Brooklyn, New York ní ọdún 1954. Ó tẹsìwájú láti gboyè àkọ́kọ́ lati ilé ẹ̀kọ́ John Jay College ní New York City ní ọdún 1968 àti JD kan láti New York Law Shool ní New York City ní ọdún 1973 .
Iṣẹ́ ṣíṣe
àtúnṣeIṣẹ́ Ológun
àtúnṣeWaldon ṣiṣẹ́ sìn ní United States Army láti ọdún 1956 sí 1959. Wọ́n fi jẹ oyè NYS Igbá-kejì Komísọ́nà fún Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn ní ọdún 1975. Ó ṣiṣẹ́ sìn gẹ́gẹ́ bí Olùgbani_nímọ̀ràn ní Ọ́fíìsì ti Mental Retardation àti Developmental Disability.
ILÉ ÌGBÌMỌ̀ ÀṢÒFIN NEW YORK
àtúnṣeWaldon jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ti New York State Assembly láti 1983 sí 1986, ó jókòó lé 185th àti 186th Àwọn ilé ìgbìmọ̀ Àṣòfin Ìpínlẹ̀ New York. Waldon jẹ́ aṣojú sí 1984 àti 1988 Democratic National Conventions. .
Ilé Ìgbìmọ̀ Àṣòfin U.S
àtúnṣeNínú ìdìbò àkànṣe láti fi kún ipò ti New York 6th congressional district ní Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣojú tí olóògbé Joseph P. Addabbo fi sílè, Waldon ni wọ́n yàn gẹ́gẹ́ bí Aṣojú Ìjọba sí 99th United States ní ọdún 1986, ó sì ṣiṣẹ́ sìn láti ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹfà, ọdún 1986, títí di ọjọ́ kẹta oṣù kìíní, Ọdún 1987. Waldon di ẹni àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ Áfíríkà _Amẹ́ríkà tí wọ́n yán an gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ Ìgbìmọ̀ láti Queens, New York .
Ní Oṣù Kẹ̀sán ọdún 1986, Waldon díje fún ìgbà kíkun, ṣùgbọ́n wọ́n ṣẹ́gun rẹ̀ ni Democratic Primary — ìdíje gidi nínú ìjọba tiwan ń tiwan tí ó lè, majority black district - nipasẹ Floyd H. Flake . Lẹhinna a yàn án Waldon sí Ìgbìmọ̀ ìwádìí ti Ìpínlẹ̀ New York.
TWaldon jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ New York State Senate láti 1991 sí 1999, ó jókòó lórí 189th, 190th, 191st, 192nd ati 193rd New York State legislature . Ni Ọdún 1998, Ó gbìyànjú láti gba ipò ilé Àṣòfin lẹ́hìn tí Flake fi ipò sílẹ̀ , ṣùgbọ́n ó dáàjí kunlẹ̀ ni idibo àkànṣe nipasẹ state Assembly Gregory Meeks .
Ikú
àtúnṣeWaldon kú ní Oṣù Kẹfà Ọjọ́ kẹsàn-án, Ọdun 2023, ní ẹni ọdún Ẹ́ẹ̀rín-dín ní àádọ́rùn. [1]
Awọn itọkasi
àtúnṣe[Alton Waldon, Retired Queens judge and former NYC congressman 1]
Ita ìjápọ
àtúnṣe- Appearances on C-SPAN
[[Ẹ̀ka:Àwọn ọmọ Ilé Aṣojú U.S. ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà]]
[[Ẹ̀ka:Àwọn ọjọ́ìbí ní 1936]]
[[Ẹ̀ka:Ilé Ìgbìmọ̀ Àṣòfin]]
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tags exist for a group named "Alton Waldon, Retired Queens judge and former NYC congressman", but no corresponding <references group="Alton Waldon, Retired Queens judge and former NYC congressman"/>
tag was found