Oníṣe:Nurudeen
Oruko mi ni Abdullateef Adewale Nurudeen
Moje eniyan ton dasi oro agbegbe, motun je akinkonju oloselu
Monife si kin ma ko awon eyan ni nkan bi imo, eyi lo mu mi loko eko bi a se n se ise oluko. Ni agbara Olorun, mo ti n se ise oluko fun opolopo odun.
Nigbati mo gbo nipa Wikimedia, ori mi wu latari ohun ti won se. Eyi lo fa ti mo fi pinnu lati ma se afikun pelu didasi ni gbogbo igba.
Lowolowo, moti se awon afikun. Mo si ma gbiyanju lati ma se sii lojojumo.