pínlò fọ́tò tí o yà nípa apá ilé ayé tí ó jẹ́ ibùgbé ohun ẹlẹmí tí àjọ UNESCO fipamọ́ ní Wikipedia fun ẹ̀kọ́ kíkọ́ àti ìwúrí gbogbo ayé.


[$wle Wiki Loves Earth] has partnered with [$unesco UNESCO] to create Wiki Loves Earth Biosphere Reserves, a photography competition to create free to use images of [$wnbr Biosphere Reserves] around the world on Wikimedia Commons, the media site for [$wp-portal Wikipedia]. Wiki Loves Earth tí ní ìbáṣepọ pẹ̀lú UNESCO lati ṣẹ̀dá Wiki Nifẹ́ Àwọn Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí tí a fi Pamọ́, èyí tí ó jẹ́ idije fótò yíyà lati ṣẹ̀dá àwòrán ọ̀fẹ́ ti Àwọn Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí tí a fi Pamọ́ káàkiri gbogbo ayé ní Wikimedia Commons, ojú òpó mídía fún Wikipedia

Wọ́n máa ṣàfihàn àwòrán mẹwá tí ó bá gbégbá orókè ní ojú òpó búlọ́ọ̀gì Ọkunrin UNESCO àti ojú òpó wẹ́ẹ̀bù ti Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí, àwọn oníṣẹ́ ìtàkùsọ́rọ̀ UNESCO máa pín wọn, tí wọ́n sì máa dije nínú international Wiki Loves Earth competition.


10 winning images will be featured in a blog post on the UNESCO Man and the Biosphere website, shared by UNESCO social media accounts and go through to the [$wle-rules international Wiki Loves Earth competition].

Wiki Loves Earth jẹ́ ìdíje fọ́tò yíyà gbogboògbò nípa àwọn ibi àdáyébá tí ó wà lábẹ́ ààbò, ní ọdún 2015 àwòrán tó ju ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgọrún ni àwọn tí ó kópa lati orílẹ̀ èdè mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n tẹ̀ wọlé. Wiki Loves Earth tún ń ṣẹlẹ̀ fún gbogbo agbèègbè tí ó wà lábẹ́ ìdáàbòbò ní àwọn orílẹ̀ èdè kọ̀ọ̀kan, wọlé síbí lati mọ̀ si nípa bí o ṣe lè kópa.

is an annual international photo contest of protected natural sites, in 2015 [$wle-2015-winners over 100,000 images were entered from 26 participating countries]. Wiki Loves Earth is also taking place for all protected areas in some countries, click here to find out more and take part.


[$bioreserves Biosphere Reserves] are areas of terrestrial and coastal/marine ecosystems or a combination thereof, which are internationally recognized within the framework of UNESCO’s Programme on Man and the Biopshere (MAB). Each Biosphere Reserve promotes solutions reconciling the conservation of biodiversity with its sustainable use. Today there are 669 biosphere reserves in 120 countries belonging to a World Network of Biosphere Reserves.

[http://www.unesco.org/new/en/natural-sciences/environment/ecological-sciences/biosphere-reserves/ Àwọn Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí tí a fi Pamọ́] jẹ́ àwọn agbèègbè orí ilẹ̀ àti omi tàbí méjèèjì, tí gbogbo àgbáyé mọ̀ níkawọ́ àwọn ètò àjọ UNESCO fun Ènìyàn àti Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí (MAB). Ìkọ̀ọ̀kan Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí tí a fi Pamọ́ máa ṣe ìgbéga àwọn ọ̀nà àbáyọ lati ṣagbátẹrù ìtọ́ju ìpínsíyẹ́lẹyẹ̀lẹ Ohun Ẹlẹmí fún lílò. Loní, Àwọn Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí tí a fi Pamọ́ jẹ́ 669 ní orílẹ̀ èdè 120 tí ó jẹ́ ti àsopọ̀ àgbáyé ti Àwọn Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí tí a fi Pamọ́.

Wikipedia jẹ́ ìkan lára ohun àmúlò jùlọ fún ẹ̀kọ́ lagbáyé, tí àwọn ènìyàn tí ó ju bílíọ́nú márùndínlógún ma ń wò lóṣoosù. Wikipedia máa ń jẹ́ kí a ṣiṣẹ́ papọ̀ lati kọ́ àwọn ènìyàn lẹkó nípa àgbáyé àti bí a ṣe lè gbé ìgbé àlááfíà. O lè ya fọ́tò ohunkóhun tí ó nííṣe pẹ̀lú Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí tí a fi Pamọ́ bíi ẹ̀yà, àlà ilẹ̀, ìpínsíyẹ́lẹyẹ̀lẹ Ohun Ẹlẹmí, ìyípadà ojú ọjọ́, ìdàgbà sókè ìmúlò àti oríṣiríṣi àṣà.

is one of the most used educational resources in the world, receiving over 15 billion page views per month. Wikipedia lets us work together to educate people about the natural world and how we can live sustainably. You can take photos of any subject within the Biosphere Reserves including species, landscapes, biodiversity, climate change, sustainable development and cultural diversity.

  • Kànsí àwọn alaṣẹ Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí tí a fi Pamọ́ ní orílẹ̀ èdè rẹ kí o sì sọ fún wọn nípa ìdíje yìí


O tún lè ran àwọn ènìyàn lọ́wọ́ lati kópa

  • Pínlò iṣẹ́ Facebook yìí

Ṣe


̣*Se ìfilọ̀ ìdíje yìí pẹ̀lú àwọn ẹgbẹ́ oní fọ́tò, ilé ẹ̀kọ́ gíga àti àwọn ẹgbẹ́ tí ó bá mọ̀ pé ó lè fẹ́ kópa. Ìdíje yìí máa jé àànfàní ńlá fún àwọn àwùjọ àti àwọn àjèjì sí Awọn Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí tí a fi Pamọ́ lati ya àwọn fọ́tò àwọn ibi wọ̀nyí, àti kọ́ ẹ̀kọ́ nípa wọn síi.

  • Share the competition with photography clubs, universities and any other groups you think may be interested. The competition is an amazing opportunity for communities and visitors to Biosphere Reserves to create photographs of the sites and learn more about them.




Tún iṣẹ́ kúkurú yìí ran ní twitter ẹ


Àwọn Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí tí a fi Pamọ́


There are many other ways for Biosphere Reserves to work with Wikimedia, for more information please click here. A press release for this competition is available on the UNESCO website here and on the Wikimedia Foundation website here.

Oriṣiriṣi ọ̀nà ni àwọn Àwọn Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí tí a fi Pamọ́ míràn tókù lè gbà bá Wikimedia ṣiṣẹ́, fún àlàyé síwájú sì́i jọ̀wọ́ tẹ ibí. Ìròyìn nípa ìdíje yìí wà ní ojú òpó wẹ́ẹ̀bù UNESCO níbí àti ní ojú òpó wẹ́ẹ̀bù Wikimedia Foundation níbí.


Bí o ṣelè wọlé

àtúnṣe

Tẹ Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí tí a fi Pamọ́ nínú àwòrán ayé tí ó wà nís̀lẹ̀

  1. Click on Biosphere Reserve to go to the UNESCO page for the Biosphere Reserves to find out more about the site and links to the Biosphere Reserve website and a map where available.
  1. Tẹ̀ lórí Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí tí a fi Pamọ́ lati lọsí ojú ewé UNESCO fún Àwọn Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí tí a fi Pamọ́ fún ìwadi síi nípa ojú òpó àtí àwọn ìjápọ sí ojú òpó wẹ́ẹ̀bù Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí tí a fi Pamọ́ àti àwòrán ayé níbi ti ó báwà.
  1. Tẹ Wọlé sí ìdíje kí ó lè gbé ẹ lọsí Wikimedia Commons lati fi ẹ̀dà fáìlì rẹ fún Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí tí a fi Pamọ́ yẹn ṣọwọ́.

to upload your images for that Biosphere Reserve.


  1. Ṣẹ̀dá orúkọ oníṣẹ́ ní Wikimedia Commons tàbí kí o fi oníṣẹ́ rẹ tẹ́lẹ̀ wọlé, Jọ̀wọ́ máṣe lo orúkọ ilé iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí orúkọ rẹ.

or log in to your existing account, please do not use the name of an organisation as your username.

  1. Attach an email address to your Wikimedia Commons account in the preferences section.
  1. Fi àdírẹ́sì ímeèlì rẹ sí oníṣẹ́ rẹ ní Wikimedia Commons ní abala ààyò rẹ.
  1. Ìṣẹ̀dà fáìlì lè gba àádọ́ta àwòrán lẹ́ẹ̀kan náà. Tí ó bá wú ọ́ lati gbé àwòrán wọlé síi jọ̀wọ̀ tẹ àjápọ̀ lórí àwòrán ayé lẹ́ẹ̀kan síi. Kò sí iye àwòrán tí o kò lè gbéwọlé.

Àkíyèsí: ọ̀pọ̀lọpọ̀ Àwọn Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí ló gba àyè púpọ̀ àwọn agbèègbè, fún ìdí èyí ojú ibi tí wọ́n wà nínú àwòrán ayé kólè ṣojú ibi wọ̀nyí, àlàyé síwájú síi wà nípasẹ̀ títẹ̀lé á̀jápọ̀ sí ' Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí tí a fi Pamọ́.


Note: many Biospheres cover large areas so points on the map do not represent the whole site, more information is available by following the Biosphere Reserve link.


The upload wizard allows 50 images to be entered at a time. If you wish to enter more images please click the link on the map again. There is no limit to the number of images that can be entered.

  • Self taken; All entries must be original photographs uploaded by their authors. Photos uploaded by anyone else than author (even with permission) are not accepted.
  • Èyí tí o yà; Gbogbo àwòrán gbọ́dọ̀ jẹ́ ojúlówó àwòran tí ẹni tí ó yàá fi ṣọwọ. Àwọn fọ́tò tí ẹlòmíran yàtọ̀ sí ẹni tí ó yàá fi ṣọwọ́ máa dìkọ̀sílẹ̀.

Gbogbo àwòran gbọ́dọ̀ jẹ́

  • Uploaded during the contest period (June 5th - June 30th 2016); You are also welcome to submit photos you may have taken in the past. What matters is that photos must be uploaded during the contest period.
  • Fi àwòràn ṣọwọ́ lakókò tí ìdíje ń lọ lọ́wọ́ (Ọjọ́ karún Oṣù karún - Ọgbọ̀n ọjọ́ Oṣù karún Ọdún 2016); O tún lè fi fọ́tò tí o ti yà tẹ́lẹ́ sílè. Ohun tí ó ṣe kókó ní kí o fi fọ́tò yí ṣọwọ́ lakókò tí ìdíje ń lọ lọ́wọ́ .
  • Contain an identified Biosphere Reserve: a lists of eligible sites can be found on the map below and on the [$wnbr Man and the Biosphere website].
  • Images can be any resolution, however the images must be at least 2 Megapixels (1600x1200) to be entered into the international competition.
  • Àwọn àwòrán lè jẹ́ ìmúsí èyíkeyí, síbẹ̀síbẹ̀ ókéré jù, àwọn àwòrán gbọ́dọ̀ tó bíi Megapixels méjì (1600x1200) kí ó tó lè wọ ìdíje gbogboògbò.
  • Fi fáìlì ṣọwọ́ pẹ̀lú lílò àwòrán ayé nísàlẹ̀; Àwọn àwòran ti ó bá gbé wọlé láìtẹ̀lé ìlànà Wikimedia Commons upload wizard kó ní wọlé fún ìdíje.

Uploaded using the map below; images uploaded using the standard Wikimedia Commons upload wizard will not be entered into the competition.

  • Ọ̀fẹ́ ni o lè kópa nínú ìdíje yìí, tí kò sì sí iye àwòrán tí o kò lè gbé wọlé.

Participation in the competition is free of charge and there is no limit to the number of images that can be entered.

  • Images can be uploaded to Wikimedia Commons at any time but will not be entered into the competition outside of June 2016.
  • O lè gbé àwọn àwòrán sí Wikimedia Commons nígbàkúùgbà ṣùgbọ́n kó lè wọlé fún ìdíje lẹ́yìn Oṣù kẹfá Ọdún 2016.

Click on a Biosphere Reserve on the map below:

  • Àwọn àwòrán mẹwá tí ó bá gbégbá orókè máa wọlé fún ìdíje gbogboògbò, àwọn òfin fún ìdíje gbogboògbò wà [wikilovesearth.org/rules/ níbí]

The 10 winning images will be entered into the international competition, the rules for the international competition are available

If you are involved with a Biosphere Reserve and would like to information on other activities please click here.

Tí o bá ní ohunkohun ṣe pẹ̀lú Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí tí a fi Pamọ́, tí o sì fẹ́ àlàyé síwájú síi lórí àwọn iṣẹ́ ṣíṣe míràn jọ̀wọ́ tẹ ibí


  • Ẹranko tí Yúróòpù ti ó ń jẹ oyin (Merops apiaster) ní Ichkeul National Park and Biosphere Reserve, Tunisia. Photo by Elgollimoh, freely licensed under CC BY-SA 3.0.



Ìtúnlò àwọn fọ́tò

àtúnṣe

Àwọn iṣẹ́ ṣíṣe míràn

àtúnṣe

àwòrán Gbogbo àwọn àwòrán tí ó wà ní Wikimedia Commons àti àwọn tí a ṣẹ̀dá bí ara ìdíje yìí wà fún lílò lọfẹ́, fún àlàyé síwájú síi bí a ṣe lè tún àwọn àwòrán lò tẹ ibi.


All photographs available on Wikimedia Commons including those created as part of this competition are available free of charge, for more information on reusing the images please click here.


All photographs available on Wikimedia Commons including those created as part of this competition are available free of charge, for more information on reusing the images please click here.

Fún ìbéèrè àti àti àwọn àlàyé síwájú síi jọ̀wọ́ kànsí J.Cummings@unesco.org

For questions and further details please email $email


Ní àfikún sí Wiki Loves Earth Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí tí a fi Pamọ́ UNESCO tí ṣètò ìṣàpèjuwe Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí tí a fi Pamọ́ lábẹ́ àṣẹ Creative Commons tí wọ́n sì ń ṣiṣẹ́ àwùjọ Wikimedia lati ṣe ìyípadà wọn sí àwọn àyọkà Wikipedia fún gbogbo Apá Ilé Ayé tí ó jẹ́ Ibùgbé Ohun Ẹlẹmí tí a fi Pamọ́. Ṣe ìwadí síwájú síi níbí

In addition to Wiki Loves Earth Biosphere Reserves UNESCO have made all official descriptions of the Biosphere Reserves available under a Creative Commons license and are working with the Wikimedia community to convert them into Wikipedia articles for all Biosphere Reserves. Find out more