Onome Ebi jẹ Àgbààbọlu Óbinrin Defender ti a bini ọjọ kẹjọ oṣu May ni 1983, si ipinlẹ Eko ni órilẹ ede naijiria.Àràbinrin naa gba bọọlu lọwọ fun FC Minsk ni Belarusian Premier League, team Naigiria nigbogbo orilẹ ede ati Super Falcons[2].

Onome Ebi
Personal information
OrúkọOnome Ebi [1]
Ọjọ́ ìbí8 Oṣù Kàrún 1983 (1983-05-08) (ọmọ ọdún 41)[1]
Ibi ọjọ́ibíLagos, Nigeria
Ìga1.75 m[1]
Playing positionDefender
Club information
Current clubFC Minsk (women)
Number25
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2001–2008Omidiran Babes
2008Bayelsa Queens
2010Djurgårdens IF Dam16(0)
2010–2011Düvenciler Lisesispor7(5)
2011–2013Ataşehir Belediyespor28(21)
2013Sunnanå SK8(0)
2014–2016FC Minsk (women)37(7)
2017–2020Henan Jianye W.F.C.0(5)
2021–FC Minsk (women)19(4)
National team
2003–Nigeria women's national football team99(2)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 20:02, 29 June 2015 (UTC).

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 13:58, 12 April 2022 (UTC)

Aṣeyọri

àtúnṣe
  • Ni ọdun 2019, ó jẹ agbààbọlu Afirika akọkọ lati kópa ni mààrun idije FIFA World Cup[3].
  • Opilẹ bi aṣe ma ran awọn Ọdọmọde lobinrin lọwọ lori Bọọlu Afẹsẹgba ati pe oun ran agbààbọọlu Naigiria league lobinrin lọwọ lori akitiyan wọn[4].

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe