Onyeka Onwenu
Onyeka Onwenu (ọjọ́ìbí ọjọ́ mọ́kànlélógbọ̀n oṣù kìíní ọdún 1952[1] o si ku ni Oṣu Keje ọjọ 30, ọdun 2024) jẹ́ oniroyin, olórin, òṣèré a jíjà gbàrà ati òṣèlú ni Nàìjíríà. Ó wá láàrin àwọn tí ó má ń dá jọ fún ètò X Factor tẹ́lẹ̀.[2] Òun ni alága tẹ́lẹ̀ fún àṣà àti ìṣe fún ìpínlè Imo.[3][4][5] Òun ni adarí àti olórí Aláṣẹ fún ìdàgbàsókè àwọn obìnrin ní orílè èdè.[6]
Onyeka Onwenu | |
---|---|
Onyeka Onwenu's Presentation At The 50 Years After The Biafran War Summit | |
Ọjọ́ìbí | Onyeka Onwenu Ọjọ́kẹtàdínlógún Oṣù karún Ọdún 1961 Onitsha |
Iṣẹ́ | Olórin, Òṣèré, àti olóṣèlú |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeOnyeka jẹ ọmọ ìdílé Arodizuogu ni ìlú Ideato North ni ìpínlè Imo. Òun ni ọmọbìnrin àbíkẹ́yìn fún àwọn òbí rẹ. Bàbá rẹ̀, D. K Onwenu tí ó jẹ́ òṣèlú kú ní ìgbà tí Onyeka wá ní ọdún mẹ́rin sì inu ìjàmbá ọkọ̀.[7][8] [9][10] .Onwenu gboyè nínú International Relations and Communication láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Wellesley College, ó sì gba masters ni The New School for Social Reasearch ni New York.[11]
Iṣẹ́
àtúnṣeNí ọdún 1984, Onyeka ṣe ère ìwé ìtàn A Squandering of Riches tí ó ṣọ̀rọ̀ nípa ìwà ibajẹ àti nípa bíi àwọn Niger Delta ṣe ń sọ fún àwọn ìjọba pé kí wọn dẹkùn tí wọn ṣe bá ìlú wọn jẹ́ pelu ìdọ̀tí tí ó ń jáde lára èpò rọ̀bì.[12] Ó ṣe atọkun fún ètò "Contact" ni ọdún 1988 àti "Who's On" ni 1993 lórí NTA.
Ó bẹ́ẹ̀rẹ̀ orin kíkọ ní ọdún 1981, o kọ orin For the love of you àti Endless life.[13] [14] Òun àti gbajúmọ̀ olórin Sunny Ade jọ kọrin Madawolohun, Choices àti Wait for me.[15] Ó kọ orin Polygon tí ó sì fi yẹ Nelson Mandela sì nígbà tí ó wá sí Nàìjíríà ni 1990 lẹ́yìn tí ó kúrò ní ẹ̀wọ̀n.[16] Ní ọdún 2013, ó wá láàrin àwọn mẹta tí ó ṣe adájọ́ lóri ètò X Factor ni Nigeria.[17] Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ People Democratic Party.[18] Ó ti du ipò alága ìbílẹ̀ ni Ideato North ni ìpínlè Imo ni ẹ méjì ṣùgbọ́n pàbó ló jà sì.[19] Gómìnà tẹ́lẹ̀, Ikedi Ohakim fi ṣe alága fún àṣà àti ìṣe fún ìpínlè Imo. Ní ọjọ́ kẹrin di lógún, oṣù kẹsàn-án ọdún 2013, Olórí orile-ede Nàìjíríà tẹ́lẹ̀, Goodluck Jonathan fi ṣe adarí àti olórí Aláṣẹ fún ìdàgbàsókè àwọn obìnrin ní orílè èdè. Ní ọdún 2000, òun ati NTA jọ ní àríyànjiyàn lórí pé wọn lọ orin rẹ láì sọ fún.[20][21] Eré tí Onwenu má kọ́kọ́ farahàn ni Nightmare.[22] Ó ti kópa nínú àwọn eré bíi bíi Women's Cot, Half of a Yellow Sun àti Lion Heart.[23]
Aiyé rẹ̀
àtúnṣeÀwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Makams, Ahman (20 October 2012). "Onyenka Onwenu: Queen Of African Pop Music". Leadership. Archived from the original on 2013-09-25. https://web.archive.org/web/20130925231923/http://leadership.ng/nga/articles/38037/2012/10/20/onyenka_onwenu_queen_african_pop_music.html. Retrieved 21 October 2012.
- ↑ "Onyeka Onwenu, Toolz, MI excited about Glo X factor". Archived from the original on 12 April 2014. Retrieved 31 March 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Charles O'tudor Fetes Onyeka Onwenu". AllAfrica Global Media. http://allafrica.com/stories/200811031100.html. Retrieved 13 August 2010.
- ↑ Nwangwu, Onyinyechi. "NCAC Honours Onwenu, Samanja, Others". AllAfrica Global Media. http://allafrica.com/stories/200912240727.html. Retrieved 13 August 2010.
- ↑ "Charles O'tudor Fetes Onyeka Onwenu". AllAfrica. 1 November 2008. http://allafrica.com/stories/200811031100.html.
- ↑ "Onwenu bags FG appointment". The Nation Newspapers. 21 September 2013. Retrieved 21 September 2013.
- ↑ Amadi, Ogbonna (2 March 2012). "Onyeka speaks at 60". Vanguardngr.com (Vanguard Media). http://www.vanguardngr.com/2012/03/onyeka-speaks-at-60/. Retrieved 4 April 2014.
- ↑ "Am I married to the father of my kids? No comment ––––Onyeka Onw". Ghanaian Agenda. Retrieved 4 April 2014.
- ↑ Adetayo, Ayoola. "Onyeka Onwenu: 10 things about the legendary musician you need to know" (in en-US). Archived from the original on 2018-05-24. https://web.archive.org/web/20180524004110/http://www.pulse.ng/entertainment/celebrities/onyeka-onwenu-10-things-about-the-legendary-musician-you-need-to-know-id4844862.html.
- ↑ Plight of Widows
- ↑ "Onyeka Onwenu’s Biography". AFROBIOS. Archived from the original on 22 November 2022. Retrieved 21 August 2014.
- ↑ "Nigeria, A Squandering of Riches". BBC/NTA. 1984. Retrieved 21 September 2013.
- ↑ [label.https://www.discogs.com/Onyeka-Onwenu-For-The-Love-Of-You/release/5335012 For the Love of You}
- ↑ Endless Life
- ↑ MUSIC-NIGERIA: There’s A Message in the Sound
- ↑ Why I Wrote Winnie Mandela
- ↑ Onyeka Onwenu, M.I, Reggie Rockstone unveiled as X Factor judges
- ↑ Onyeka Onwenu gets political appointment
- ↑ [1]
- ↑ Nigerian singer on hunger strike
- ↑ Nigerian singer's hunger strike over
- ↑ Nightmare
- ↑ "AMAA 2006 – List of Winners". African Movie Academy Awards. Archived from the original on 12 February 2008. Retrieved 15 October 2010. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ https://www.legit.ng/1166292-onyeka-onwenu-husband-children.html
- ↑ https://www.informationng.com/2015/11/photos-meet-the-son-of-legendary-singer-onyeka-onwenu.html
- ↑ https://theirworld.org/news/my-inspirational-teacher-by-nigerian-singer-and-actor-onyeka-onwenu
[Ẹ̀ka:Àwọn ọmọ Yorùbá]]