Onyekachi Apam

Agbaọ́ọ̀lù ọmọ orílé-éde Nàìjíríà

Onyekachi Apam (tí a bí ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kejìlá, ọdún 1986 ní Aba) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ilẹ̀ Nàìjíríà ti tẹ́lẹ̀ tí ó fẹ̀yìntì ní ọdún 2014 lẹ́yìn tí ó farapa nígbà tí ó ńṣiré fún Seattle Sounders FC.[1] Ó ṣe aṣojú Nàìjíríà ní ọdún 2008 Summer Olympics ní Ìlú Beijing gẹ́gẹ́ bí apá kan ti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àwọn ọkùnrin.[2]

Onyekachi Apam
Personal information
OrúkọOnyekachi Apam
Ọjọ́ ìbí30 Oṣù Kejìlá 1986 (1986-12-30) (ọmọ ọdún 37)
Ibi ọjọ́ibíAba, Nigeria
Ìga1.77 m (5 ft 10 in)
Playing positionDefender
Youth career
0000–2003Pepsi Football Academy
2004–2005Enugu Rangers
2005–2006Nice
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2006–2010Nice105(1)
2010–2014Rennes23(0)
2014Seattle Sounders FC0(0)
National team
2005Nigeria U206(0)
2008Nigeria U235(0)
2007–2010Nigeria14(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Iṣẹ́ Rẹ̀ àtúnṣe

Ní ọdún 2005, Apam gbìyànjú fún OGC Nice, nibiti ó ti f'ọwọ́ sí nígbà náà. Ó ṣe àwọn ìfarahàn 105 àti pàápàá fàágùn àdéhùn rẹ̀ láti parí ní ọdún 2013 tó yẹ kó jẹ́ ọdún 2012 ṣáájú kí ó tó lọ sí Stade Rennes ni ọdún 2010.[3][4]

Àwọn Ìtọ́ka Sí àtúnṣe

  1. Mabuka, Dennis (2021-07-03). "Lesley Ugochukwu: Nigeria target signs contract extension at Rennes". GOAL. Retrieved 2021-07-21. 
  2. Azikiwe, Ifeoha. Nigeria Echoes of a Century - Volume Two 1999-2014. p. 357. https://books.google.com/books?id=mAahpzY-p78C&pg=PA357. 
  3. "Sounders FC Signs Onyekachi Apam". Sounders FC. 2014-09-19. Retrieved 2021-07-21. 
  4. "Nice's Nigerian Apam Extends Contract". GOAL.com. 2008-10-21. Retrieved 2021-07-21.