Opeoluwa Sotonwa (tí wọ́n bí ní Ijebu-Ode) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America. Arákùnrin yìí jẹ́ agbẹjọ́rò fún àwọn odi, ajàfẹ́tọ̀ọ́ àwọn odi[1] àti òǹkọ̀wé ìwé lítíréṣọ̀.[2] Ní oṣù February, ọdún 2021, Gómínà Charles Baker yàn án sípò Kọmíṣọ́nà àti olórí Massachusetts Commission fún àwọn odi. KÍ wọ́n tó yàn án sípò yìí, ó jẹ́ adarí àgbà fún Missouri Commission fún àwọn odi.[3][4][5]

Opeoluwa Sotonwa

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Presenters | NAD". new.nad.org. Archived from the original on 2015-12-08. Retrieved 2015-12-02. 
  2. Stremlau, Tonya M. (2002-01-01). Deaf Way 2 Anthology. Gallaudet University Press. ISBN 9781563681271. https://books.google.com/books?id=Zn4-CT704sUC&q=opeoluwa%2520sotonwa&pg=PA89. 
  3. Shahla Farzan (September 2, 2019). "State Program Aims To Help Missouri Residents Purchase Hearing Aids". St. Louis Public Radio. https://news.stlpublicradio.org/health-science-environment/2019-09-02/state-program-aims-to-help-missouri-residents-purchase-hearing-aids. Retrieved December 23, 2020. 
  4. "Archived copy" (PDF). Archived from the original (PDF) on 2015-12-08. Retrieved 2015-12-01.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. Rebecca Smith (June 29, 2020). "COVID-19 & ASL Interpreters: 'For the First Time, Many Missourians Felt Their Voice was Recognized'". University of Missouri School of Journalism.