Orílẹ̀-èdè erékùṣù

(Àtúnjúwe láti Orílẹ̀-èdè erékùsù)

Orile-ede erekusu je orile-ede ti gbogbo agbegbe re je erekusu kan tabi jubelo tabi to je apa erekusu. Ni 2008, orile metadinladota (bi 25%) ninu awon orile-ede aye ni won je orile-ede erekusu.

Island countries in the world
Countries without land borders