Orílẹ̀-èdè kọ́múnístì
Orílẹ̀-èdè kọ́múnístì (communist state) je orile-ede alaseorile to ni iru ijoba ti iwa re je ti ijoba egbe oloselu kan tabi ijoba egbe oloselu togbaleju to je egbe oloselu komunisti to si di ero-oro oselu komunisti mu gege bi ilana opo orile-ede.

Maapu awon orile-ede komunisti lowolowo ti won ni ijoba komunisti/sosialisti. Awon ni Saina, Kuba, Laos, Vietnam, ati Korea Ariwa.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |