Orúkọ ìdílé tàbí orúkọ àpèlé ni apá kan nínú gbogbo orúkọ ènìyàn tó tọ́ka sí ìdílé oní tọ̀ hún (tàbí ẹ̀yà, tàbí àwùjọ oní tọ̀ hún, gẹ́gẹ́ bí àsà wọn).[1]