Jíjẹ́ orúkọ

Kò sí ẹnìkan tí njé áwádé òpò ènìyàn ní ń jẹ́ janmọ. àwon yorùbá sì má ń sọpé orúkọ ọmọ ní ijanu ọmọ. Kí oníkálukú ní orúkọ ló ṣe pàtàkì. ìdí pàtàkì ni èyí tí a fi ń ṣọmọ lórúko. Yorùbá bò wón ní òwe lẹ̀sín ọ̀rọ̀ ọ̀rọ̀ lẹ̀sín òwe,bọ́rọ̀ bá sọnù òwe ni a fí ń wa. Bí a bá ṣàkíyèsí ọ̀pọ̀lọpọ̀ òwe yorùbá,a o rí I dájú pé yorùbá kìí dédé ṣọmọ lórúkọ.