Ọ̀rànmíyàn
(Àtúnjúwe láti Oranmiyan)
Nínú ìtàn àròsọ/àtẹnudẹ́nu ilẹ̀ Yorùbá Ọ̀rànmíyan tàbí Ọ̀rányàn jẹ́ Ọba Láti Ilé-Ifẹ̀ bẹ́ẹ̀ ni ó tún jẹ́ ọmọ Odùduwà. Ohun ni ìtàn àròsọ ẹnu yí sọ wípé ó dá ìlú Ọ̀yọ́ sílẹ̀. [1][2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Babarinsa, Dare (2019-04-25). "The restless children of Oranmiyan". The Guardian Nigeria News. Archived from the original on 2019-11-23. Retrieved 2019-11-23.
- ↑ oloolutof (2017-02-24). "Oranmiyan Omoluabi Odede the first Alaafin of Oyo". Yoruba Traditional & Cultural Renaissance. Retrieved 2019-11-23.