Àgbájọ fún Ìdènà àwọn Ohun Ìjagun Ògùn Olóró

Àjọ tí ó ǹ rí sí ìdènà ohun ìjà ogun olóró (OPCW) jẹ́ àgbáríjọ àwọn ìjọba orílẹ̀-èdè àgbáyé intergovernmental organisation, tí olú iléeṣẹ́ wọn wà ní ìlú The Hague, ní orílẹ̀-èdèNẹ́dálaǹdì.

Organisation for the
Prohibition of Chemical Weapons
Fáìlì:OPCW logo.gif
OPCW logo

Member states of the OPCW (green)
Formation29 April 1997[1]
HeadquartersThe Hague, Netherlands
52°05′28″N 4°16′59″E / 52.091241°N 4.283193°E / 52.091241; 4.283193Coordinates: 52°05′28″N 4°16′59″E / 52.091241°N 4.283193°E / 52.091241; 4.283193
Membership190 member states
All states party to the CWC are automatically members.
6 states are non-members: Angola, Burma, Egypt, Israel, North Korea and South Sudan.
Official languagesEnglish, French, Russian, Chinese, Spanish, Arabic
Director GeneralAhmet Üzümcü[2]
Official organsConference of the States Parties
Executive Council
Technical Secretariat

Àjọ yìí ń ṣègbé-lárugẹ ìfohùn-ṣọ̀kan lórí àwọn ohun ìjà ogun olóró onírúurú Chemical Weapons Convention ní èyí tì ó dènà lilo ohun ìjà kẹ́míkà okóró chemical weapons èyí tí ó lè mú ìparun wá. Ìfọn rere rẹ̀ yóò wáyénígbà tí àwọn orílẹ̀-èdẹ tí wọ́n jẹ́ alámòójútó bá ti fẹnu kò wípé kí ó rí bẹ́ẹ̀, lẹ́yìn tí wọ́n bá ti ṣàgbéyẹ̀wò rẹ̀ kíní kíní.


Àwọn Itọ́ka sí

àtúnṣe

Àdàkọ:''Ìkọ awọ́lẹ́ẹ̀gbẹ́''Reflist

  1. "Chemical Weapons - Organisation for the Prohibition of Chemical Weapons (OPCW)". United Nations Office for Disarmament Affairs. Retrieved 2013-10-11. 
  2. Oliver Meier and Daniel Horner (November 2009). "OPCW Chooses New Director-General". Arms Control Association. http://www.armscontrol.org/act/2009_11/OPCW.