ORIN ÌMỌ́TÓTÓ

Wẹ̀ kí o mọ́

Gé èékánná rẹ

Jẹun tó dára lásìkò

Má jẹun jù.


Ìmọ́tótó ló le ṣẹ́gun ààrùn gbogbo

Ìmọ́tótó ló le ṣẹ́gun ààrùn gbogbo

Ìmọ́tótó ilé, Ìmọ́tótó ara

Ìmọ́tótó oúnjẹ

Ìmọ́tótó ló le ṣẹ́gun ààrùn gbogbo